Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2010

Lyrics

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo

Ishoro aye re jesu afi opin si

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo (x2)


Nipa igbagbo oba jehosaphath

O fiyin folorun o bori ogun awon ara moabu

Beno ni o bori ogun awon ara amoni

Ati awon ttin gbe oke seri

Aye tere osin mi lowo ogun

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo


Nipa igbagbo shederach meshach ati Abednego

Won fiyin fun olorun ninu ino eleru

Won bori ogun ogun eni eniyan

Toun pe eni eniyan mimo lakoko yen

Aka imoye egbegberun eniyan

Ni won tipase shedrach meshach ati Abednego

Gba jesu Kristi ni olua ati oluagbala

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo


Nipa igbagbo shederach meshach ati Abednego

Won bori gbogbo ogun ishoro o laye

Nipa igbagbo ayanfe omo olorun

Paul ati sialas won bori ishoro

Won fiyin fun olorun ninu ide won

Ninu ishoro won o se jesu

Won dupe lowo olorun oga ogo

Woni igbagbo wipe oba to ja ide heberu meta

Yio ja ide won

Won fiyin folorun aka imoye emiyan nipase won won gba jesu gbo

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo


Ayanfe omo olorun ton ngbo mi oro wa kan o

Tori akoko o kuru fun mi o ara

Lati lo so gbogbo itumo oro yi tan

Toba ti ni igbagbo ninu jesu oluwa

O bori ishoro aye re

Awon gbogbo ti mo soro nipa re

Gbogbo won ni won jeri si agbara olorun

Iwo lo ba ni igbagbo ninu jesu

O bori ishoro aye re

Shama dupe o oro tire a dayo

Ore fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo


Jesu Kristi oluwa wa oga ogo

Nibi oku lazaru o fiyin folorun

Oba tin je emi ni olorun gbagbo

Ishoro aye re eyi to la koja

Toba tini igbagbo ninu jesu oluwa

O fise itan pa

Awon ayanfe olorun ti an soro nipa gbogbo won

Gbogbo won ti won la ishoro koja

Gbogbo won lo fiyin folorun o

Toba tini igbagbo ninu jesu oluwa

Dupe lowo oga ogo

Oro tire baba so dayo

Ekun re loni baba so di erin lola

Aiyini tire baba mi a so dopo

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo


Ayanfe omo olorun

Ishoro agan eyi ton la koja

Oba tin dahun adura Elizabeth

Egan tire baba mi a gba osi so di ogo

Loju ara adugbo to bi o alajogbe

Ninu ile baba tabi ninu ile iya

Larin egbe o tabi larin ogba

Ninu ijo olorun araye ko ma mo o

Oba tin dahun adura a gboro re ro o

Toba tini gbagbo solorun

Ayanfe mo olorun


Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo

Ishoro aye re jesu afi opin si

Fi igbagbo yin jesu logo

Fi igbagbo yin jesu logo


Lori omo re o

Fi igbagbo yin jesu logo

Eyi to ya alayi gboran si o se

Fi igbagbo yin jesu logo

Toba le dupe lowo jesu

Fi igbagbo yin jesu logo

Ayi roko fe logun tire ore

Fi igbagbo yin jesu logo

Oba to pese Isaac ni

Fi igbagbo yin jesu logo

Fun rebecca lojo ojo si

Fi igbagbo yin jesu logo

Igbeyawo tire ani arinrin o

Fi igbagbo yin jesu logo

Oba tin dahun adura lolorun o

Fi igbagbo yin jesu logo

Araye si ma ba o yo se

Fi igbagbo yin jesu logo

Promotion logun tire ore o

Fi igbagbo yin jesu logo

Oba to gbe modikai ga lojosi

Fi igbagbo yin jesu logo

Yio gbe o ga larin egbe ore

Fi igbagbo yin jesu logo

Oba to gbo adura obedi odomu

Fi igbagbo yin jesu logo

O so doloro ninu iran re

Fi igbagbo yin jesu logo

Ore mi ni gbagbo o

Fi igbagbo yin jesu logo

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status