- Genre:Gospel
- Year of Release:2014
Lyrics
Elu Agogo - Another Creation Communication (David Aina & The Adun Minstrel)
...
Elu agogo )3ce
keresimesi
Elu agogo oooo
Elu agogo Olugbala de o
elu agogo
Awon oluso aguntan
won so eran won
imole yi won ka
won ni kilode
ase Olugbala la bi
Olugbala wa kabo
Elu agogo)3ce
keresimesi
Eluagogo ooo
Elu agogo olugbala de o
elu agogo
Iranwo kan yoo soju orun si oba meta
Awon angeli korin won pe Olugbala won ti de
Olugbala wa kabo
Elu agogo)3ce
keresimesi
elu agogo ooo
elu agogo Olugbala de o
elu agogo
Afope fun Baba
Omo
Emimo
ko lugbala to de
Olugbala wa kabo