85 Redeemed Yoruba Worship Songs Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2016
Lyrics
85 Redeemed Yoruba Worship Songs - Shaba Ark Okiki
...
Ta lo da bi ire Jesu
Ta lo dabi ire oo alagbara
Talo dabi ire Jesu
Talo dabi ire o alagbara
Oba to gbe ogo kari ogo oo
Lati inu ogo lo sinu ogo
Oba ti ki n sun
Oba ti ki n re
Talo dabi ire o alagbara
Tala le fi o we oo, Tala le fi we o
Mo wa titi mi o ma ri Ninu aye yi
Sebi iwo lalagbara giga
Oba ti o se fi we enikankan
Iwo ni baba to ba Lori oun gbogbo
Tenikeni o le ba le lori
Ire loba ti ki n sun rara o
Iwo loba ti ki n re
Sebi iwo lalagbara giga oo
Olorun awa oo
There is no one like you baba
Sebi iwo ni kabiyo o si o
Eni ti o bi o, won o ti bi
Be, o da mi loju wipe won o le bi eee
(back to chorus)
Ko ni da ti o ba yin
Gbo mi daadaa
Inu iyin ye n gan ni isegun ti e wa
Tori gbogbo I oran aye Lori aye re ko je ko wa si imuse, ko fun esu laye ati segun Lori aye e
Why won't I praise him?
Bo ba je emi ni o ni, ma yira mo le lati ma yin
Baba ese jesu ese f'ore te se fun mi
Baba ese jesu ese f'ore te se fun mi
B'aye ti fe fun mi ko Lori
Mo wa yin o logo
Baba ese jesu ese f'ore te se fun mi
(repeat)
Jesu mo wa dupe mo to pe da Lori aye mi o
F'ore te se fun mi
O je ki ife satani o se Lori aye mi o
Kristi mo dupe lowo re o
Fun oju rere to fi Han nise mi
Tori wipe, baye ti fe fun mi ko Lori oo
Emi wa, mo wa yin o logo
Baba ese olufe okan mi o mo mope wa
F'ore te se fun mi
(back to chorus)
Gba gbogbo ogo jesu mi o tire ni
Gba gbogbo ogo, Jesu mi o tire ni
(all) Gba gbogbo ogo jesu mi o tire ni
Gba gbogbo ogo, Jesu mi o tire ni
Bo ba gba lowo mi, kkko seni ti mo fe gbe lo fun o
Eleburu Ike o, sebi iwo lo ni gbogbo ogo
Ogo re yu gangan baba mi, iwo ko ni pin pelu elomi oo
Kristi mi o, tire ni
Gbagbagbagba gba gbogbo ogo
(back to chorus)
Gbogbo igba toju mi ba Rojo tuntun
Ma l'oluwa eseun, oluwa eseun
Gbogbo igba toju mi ba Rojo tuntun
Ma l'oluwa eseun, oluwa eseun
(repeat)
Ni gbogbo igba ti oju mi ba ti ri ojumo
Ma dupe fun idasi emi o
Idasi emi o
Nigbakigba ti n ba ji, ma so pe baba ese, ese o
Ma loluwa o Seun, oluwa o Seun
(back to chorus)
Ogo ni fun baba ni Oke amin
Ogo ni fun baba ni Oke amin
Toranu re duro titi Lai, amin
Toranu re duro titi Lai amin
Ogo ni fun baba ni Oke amin
Ogo ni fun baba ni Oke amin
Toranu re duro titi Lai, amin
Toranu re duro titi Lai amin
Ogo lo ye fun baba ni Oke orun
Gbogbo awa ta n be laye yi o
Eje ka dupe folorun orun
Tori anu re duro titi Lai Lori wa
Tori anu re duro titit Lai, amin
Gba ogo baba
Gba ogo omo
Gba ogo emi mimo
Mo ti rayo gba