Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2012

Lyrics

Alaanu Igi aruwe - Lekan Remilekun Amos

...

instrumental

asiko Sha ni gbogbo nkan oo

igba Sha ni gbogbo nkan erora

asiko Sha ni gbogbo nkan o late

igba Sha ni gbogbo nkan erora

eso fun enikanju koja akoko

ko ni jere bo koni de ba ohun too ni

eni leku meji loojo

agbagba fowo soya pe oni lati pofo dandan

Tori olorun gbon ju eda lo

instrumental

repeat chorus.



ojumo nigba erun oju orun funfun

arope yio ran orun to yio my ojo gbona

sugbon iseju kan so keji yen o

odi dudu on fi agbara rojo owan Yani lenu tani je bi olorun lere



eeni suuru oo eeni suuru oo

eni suru oo eniyan

eeni suuru oo

tori aiye ti awa kogba Kira kita mo

ohun gbogbo si n fe eso eso eni suuru oo

oba to da wa ti mo pe Oye ka je

oba to da wa ti mo pe Oye ka my

die pelu iteloru ere nla

sho wa ye kawa eni dabi eledumare eeni suuru oo


repeat chorus


iwe oniwasu lojen mo

arami

pe orisirisi igba lolorun wa da

igba kiku,yiye,gbigbin pelu igba tao ka bose hun olorun ni se ola gbogbo.

iyen nipe asure tete ko ni koja ile

Arin gbere ko ma ni sun Sona

iponju tilu opo emi pa oso opo di abirun eenisuuru oo

opo sare ju igba won ku lomode

opo fe firiju lo ipin won ko gba

bi gba oba to da wa loke ko ba to

gbogbo lala omo enia bi eso ti ko ladun eeni suuru oo

repeat chorus

instrumental

ohun to oje teni ma ni bani kale

ohun afi ikanju se kimai pe pupo

ara egba fun eledumare ko ma dari wa,aditu nise re ko seni to letuwo

eenisuuru oo

morantibpe Elisha se kilo pe asikokoto gbo e

gehazi ko ikilo emi ogbe eye namani

bi aba ronu jinle iruwon yen nko

koma to kawa eniyan dari eledumare eeni suuru oo

hanania gbero lati firiju di olola

oyi Ilana aposteli po oku lojiji

bi aba ronu jinle iruwon yen nko

ko ma to kawa eniyan dari eledumare oba eeni suuru oo

Tori ohun gbogbo pelu asiko 2ce

eda duro de igba yin

ohun gbogbo pelu asiko 2ce

duro de igba

eda made kanju

kanju ju olorun lo

ohun gbogbo pelu asiko 2ce


eni leku meji kiyio ri pada

kama dari olorun

togbon ju wa lo

ohun gbogbo pelu asiko 2ce

eda made kanju Yee mobe oo

esofun won pe ko mase kanju

to gahazi kogbon

efi hanania kogbon

ohun gbogbo pelu asiko 2ce

ohun gbogbo

yep mobe

alore de tan ohun gbogbo pelu asiko

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status