Oroki Social Club (Osogbo) Lyrics
- Genre:Apala
- Year of Release:1971
Lyrics
Oroki Social Club (Osogbo) - Alhaji Haruna Ishola & His Apala Group
...
mo kan Sara so won bi won ti nse
isunmoni lan mo se eni
oroki social club nilu oshogbo
Olawale Oladiran president egbe won ni.
oroki social club nilu oshogbo.
Kolapo igbalaye vice president won.
oroki social club nilu oshogbo.
alafe ni e Dejo Babalola
secretary egbe won ni
oroki social club nilu oshogbo
Adeleke Oduola treasurer
gbogbo won loti rihun jaje o
yato si pako bi e d'oshogbo
e o ri bi won ti n se
eyan pupo nlanla jo nse po
won fera won de'nu
eni ba ri won nla ti kan Sara si won
otito ti won ni ohun lo je kegbe yen dun o
bo ti ndun yi a dun do'jo ale ase o e.
ojojumo la n ranti yin.
oroki social club nilu oshogbo.