Olorun Majemu Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2020
Lyrics
Olorun Majemu - Esther Igbekele
...
majemu to baye mi da o
ileri to fi se didi fun mi
mase je o pe koto dami lohun
bami she o Kogo mi o bu yo
majemu to baye mi da o
ileri to fi se didi fun mi
nase je o pe koto dami lohun
bami she o Kogo mi o bu yo
edidi oro...oya bami faanu yanju e
iwe genesisi ori ketadinlogun o
bere lati ese kini lo mu mi ranti majemu yen
eyi tolorun ba abrahamu da lojo yen
wipe toba rin niwaju ohun to ba si ke o
ohun aso di pupo adi baba orileede pupo
awon oba alade atun ma jade lati nu Iran omo re wa
iyen niwipe tori kan ba sunwon oni lati ran gba
melo wa ni ododo mi niwaju re eledumare
teje re ni ko saaro olorun ko saanu fun mi
oni ti n ba sin e wa so mi doloro to po laye
bamishe o baba maje koju o ti mi laye mi
ojo ori mi nlo o ma n lo die die
teje re ni kooro olorun wa mu majemu she
tori to ba lo peju aye afi mi bu o o baba.....
majemu to ba ye mi da o
ileri to fi she did fun mi
mase je o pe koto damilohun
bamishe o kogo mi o buyo