Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2012

Lyrics

Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oun ti ati foro ibaje ninu aiye mi

Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oun ti ati foro ibaje ninu aiye mi

Oro kan soso ole tunse oro kan soso


Oro laseda fi da aiye atorun

Oun gbogbo to wa ninu re oro lo fi da

Baiye ati orun ba yi pada oro olorun yio wa titilaye

Tori oro ledidi oun gbiogbo


Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oun ti ati foro ibaje ninu aiye mi o

Oro kan soso ole tunse oro kan soso


Oro lagbara ewa wo do oro aiye

Oun taiye pe loro ni gboloun

Ninu oro aiye n iwo so ofo

Ninu oro won ni ase

Oun oro aiye se fun aiye

Janba lo po ninu won

Oruko taiye ba poro ni yio je

Ibi ni won fi un se fun ra won

Eda gbogbo tin gbaiye e ma ba mi bo o

Ibu do kan ero to lo si irin ajo

Lapero soko tin pariwo ewole hundred naira lowo ori enikan

Onikaluku wolel soko loko ba kun i won ba si

Won mori le irin ajo won

Igba to mi a gbowo oko tan pata

Baba kan lo ko to loun o ni san wo

O san hundred naira o fe gba forty naira pada

Gbogbo ero to wa ninu oko won ko ah unpe baba se’be ti gbo tele

Conductor loun o ni gba labo baba loun oni won kun

Enikan ninu oka loun afi kun

Baba ba ni ko ni dara fen i ba fi kun

Gbogbo ero to be ninu oko ba gbenu won dake

Igba baba de bi to nlo lo ba wo conductor sokale loko

Lo ba ni o gbe ka to wi ka to fo ero to pe le won lori

Ijanba laiye ma fi wa beeni

Ba gbara aiye ba tin wun won

Bi ka ban ju eniyan ibi won ma to ja ta se kiri

Oro ni won fin ja ewa wo di oro taiye pon le

Loba pase latinu oro ta wa ninu ta wa ninu olorun ti a ko ri

Ko to wi tan conductor ti bo so so nu un lo ba mori le gbo

Se ti waiye oro agbara aiye opelope arakunrin kan

Ton be ninu oko to je omo olorun to mo iseda

To da aiye to moun gbogbo oro olorun to ni pa

Oro eyi ti ati ko wipe ko soun ija kan ti a se si o

Ti o pa o lara ati pe la leni nah tin wi to si se

Nigbati oluwa ko pase re oo

Nitori nah ni oruko jesu olugbala conductor pada w a bi

Woso kori e si pe lara ba ro baba oloro aiye

Abi e o ro oro to ro bi bi ko ba se ti jesu

Opo eda lo ti deja ko sa won won


Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oro kan soso ole tunse oro kan soso

Oun ti ati foro ibaje ninu aiye mi


Eniyan ninu aiye eje ka fura o

Satani un soro bii a pon

Elomiran ki a to bi won o

Lowo awon ota ti te won

Elomiran nigba ta bi won tan

Larin egbe nibise oro ikan ta gbeleni lori ta omo lori sirisi ika ba tin se ni


Eje ka gbadura eniyan o

Kaiye ma fowo tun ni da

Mo fowo de le da mi mu

Kori mi ma gbabode oro o


Oro kan soso toseda aiye oro kan ni

Oro kan soso ton gbe oro mi oro kan soso

Oun ti ati foro ibaje ninu aiye mi o

Oro iseda o so won di re pada o oro kan o

Oro kan soso toseda aiye oro kan ni

Oro kan soso ton gbe oro mi oro kan soso

Oun ti ati foro ibaje ninu aiye mi o

Oro iseda o so won di re pada o oro kan o

Oro kan soso toseda aiye oro kan ni

Oro kan soso ton gbe oro mi oro kan soso

Oun ti ati foro ibaje ninu aiye mi o

Oro iseda o so won di re pada o oro kan o

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status