Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2018

Lyrics

Gbogbo Were - 9ice

...

Aye kí mo wà

Orí ayé

(Chrs)

Ayé kí mo wà

Bí mi ò lowo lọ′wọ'

Ayé kí mo wà bí ń bẹ gbé pe

Ayé kí mo wà bí ń kó lè mole

Kàkà ki n wa yẹ rare

Má tí gbogbo wéré bo

Má yà tí gbogbo wéré bo

Gunugu mi ò ní kú lè we

Má yà tí gbogbo wéré bo oo

Má yà tí gbogbo wéré bo oo

(Stanza 1)

Wọn na náírà

Mo ń náà dollar

Wọn ní mo ṣe sọ

Wọn lọ Russia

Mo lọ Canada

Wò ní bo loti rowo

Ota ó mọ pe owo ni koko

Owó di dandan

Báwo ló ṣe se

Kan má bi mi

Kan ló b′Olorun lejo

Itakun to so gba

Lọ sọ elegede

Èmi ti mo kò lè na

Náà ni mo tun wá silẹ

Anywhere money dey

I go dey

Anywhere blessing dey

I go dey

Life without money

I no dey. I nodey. I no dey eeeh...

(Chrs)

Ayé kí mo wà

Bí mi ò lowo lọ'wọ'

Ayé kí mo wà bí ń bẹ gbé pe

Ayé kí mo wà bí ń kó lè mole

Kàkà ki n wa yẹ rare

Má tí gbogbo wéré bo

Má yà tí gbogbo wéré bo

Gunugu mi ò ní kú lè we

Má yà tí gbogbo wéré bo o

Ma yà ti gbogbo wéré bo oo

(Stanza 2)

Ta ló ń jẹun

Tí ajá ń ju irú gan naa

Gangan naa

If money dey

Friends go come, family go talk dem belong

If money no dey

Ìwọ ni kan ló má dá ran

Ṣe rí p ′owó di dandan

Olúwa wa kò bá wà tán ọ′ràn naa

Leyin owó. Owo ni

Leyin owó. Owo ni

Owó là fi ń kólé

Owo ni a fi ń sá yẹ

Owó là fi ń Segun ota

Owó ni a fi ń gbé lé pá ota

Owo la fi ń ṣe ọkọ obìnrin

Owó óò... Ìwọ ro oooo

(Chrs)

Ayé kí mo wà

Bí mi ò lowo lọ'wọ′

Ayé kí mo wà bí ń bẹ gbé pe

Ayé kí mo wà bí ń kó lè mole

Kàkà ki n wa yẹ rare

Má tí gbogbo wéré bo

Má yà tí gbogbo wéré bo

Gunugu mi ò ní kú lè we

Má yà tí gbogbo wéré bo o

Ma yà ti gbogbo wéré bo oo

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status