Omo Ranti Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Omo ranti ooo omo ma gbagbe ee
Omo eniti iwo un se
Igbala ni asiko imo re tide o
Omo ma gbagbe eleda re
Omo ranti ooo omo ma gbagbe ee
Omo eniti iwo un se o o o
Igbala ni asiko imo le yio
Omo ma gbagbe eleda re
Ile ti a fi to omo eriri o wo o
Omo ti o ni afarada yio san eje fun atunbotan
Igba lo do ni l’aiye
Agba fere kan odo na o
Tara shasha omo lopin re ko da (Se kia ooo)
Omo ranti ooo omo ma gbagbe ee
Omo eniti iwo un se ooo
Igbala ni asiko imo re le yi o
Omo ma gbagbe eleda re
Ta ba ba o wi to ba warun ki
Awon agba l’omo ti a o ko a gbele ta k ta oo
Shasha l’omo ta o ko o iwo l’omo ton gboran
Omo ma pami to ba se die o ma di omo ma para re
O ti to ju bo o ti yan eyi o fe yan lo ya
Bo ba ranti oni gba lo so iya re loruko (oun o ba pe ra re)
Omo ranti ooo omo ma gbagbe ee
Omo eniti iwo un se ooo
Igbala ni asiko imo re le yi o
Omo ma gbagbe eleda re
Oporo omo ti ba aiye lo o
Won ti ka sa di daku da
Okunrin ole dobale ki agba
De bi obirin a kunle ki eni to ju
Oro alufansha lenu won
Awon omo ibi ni ran
Aiye baje ema ma pe odara (o gede baje e ma so pe o pan)
Omo ranti ooo omo ma gbagbe ee
Omo eniti iwo un se ooo
Igbala ni asiko imo re le yi o
Omo ma gbagbe eleda re
Suru baba imo kin se todo iwoyin mo o
Odo aiye ti to wo bo ibokubo
Afayi to jelete ma mi bi erini logun
Omo ti o ga nu le ni o mu
To wa fi emi fa bu owo
O fe di borogini lawu jo
Moto ata ile alara golu iye bi ye lo fera o
Ema gbagbe aje weyin
Yio pelede ijosi
Iku ojiji dede lo fimisere
Ma fi emi e toro fun satani
Jowo ronu omo ranti
Omo ma gbagbe eleda re
Omo ranti ooo omo ma gbagbe ee
Omo eniti iwo un se ooo
Igbala ni asiko imo re le yi o
Omo ma gbagbe eleda re
Be o ba gboro obi o
Te o tun gbo t’olorun
Dede iku be lo de o (iku ma nbe lode o polowo)
Eya dakun e gboro mi
K’eya gbo tebi o (yungba yungba adun yi wuni ninu)
Ke ma pa obi yin lekun
Ke ma so won di agan ale (yungba yungba ewu pani lara)
O o ni le jakara ore ko tun mu dani
E sin to ko sare iran nio wo gbeyin
O le rin irin a jo ko tun wa ni ile
Ko ma lo je gbin ko ma lo kuku gbin (wa keni ko to keji dandan ni)
Ayi ka wa ayi gbeko
O fe yege elere jele a le ra re fun ekun pa
Ma fi egbe okunkun di alagabara
Ko ni le llora emi re (a yo ada a yo obe a kun e bi alapata)
Ranti elede re nigba ewe re jesu feran re
Igbati ojo ibi ko yi de
Ogo olorun loje ma ma je ki eseun o yo o subu
Fi ogo olorun han lona gbogbo
Ma je ko oun aiye tan pa o jare
Ki lere eleda re ton pe o ni ini oru
Omo pade ba eleda re laja
To ba le yi pada ko se atunse aiye re
Dede ni o ro koko re lagbala (olowun rere fun o ni pamo)
Ma wo bi okunkun ti o ti wo rin jina pada ole gba o se kia
Dede ni o ro koko re lagbala (ojo iwaju e o ma daa)
Ma beru eni olorun le pa
Eni to to ni gba ni o sa wa ba o
Dede ni o ro koko re lagbala (eto to fi sile fun o ju wuraa iye bi ye lo)
Jesu un duro lenu ona o pe o omo wole wole wole