Ibinu Isinmi Laya Were Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Okunrin a fa bo sile obirin roja a pada bo
Egbo eni rajo gbogbo se ni won fabo sile o
Ori mi jo o eda mi jowo bi mob a roja tojo terun abo mi kodara
Okunrin a fa bo sile obirin roja a pada bo
Egbo eni rajo gbogbo se ni won fabo sile o
Ori mi jo o eda mi jowo bi mob a roja tojo terun abo mi kodara
Aseda to da aiye o o da oun gbogbo si ile aiye
Owa da eniyan lawo ran arare o fi wa joba lori won
O da wa sile aiye lati wa joro oun gbogbo to da
Aiye lo fi se oja se wa ri orun ile wan ni
Okunrin a fa bo sile obirin roja a pada bo
Egbo eni rajo gbogbo se ni won fabo sile o
Ori mi jo o eda mi jowo bi mob a roja tojo terun abo mi kodara
Ahah aiye wa dabi oja tami na laiye
Tolukuluku na ja re ti yio fi pada sile
Eni lowuro a se owuro eni losan ko ni dale
Oloja ale a na tire gbogbo eniyan ni yio re le
Sugbon bot i wu koja pe to ken i to na ja pe to
Eda e ma ja gbagbe rara ile la bo simi oko (ile labo simi oko)
Ori mi jo o eda mi jowo bi mob a roja tojo terun abo mi kodara
Eni to ran wa o jin yi fun eda e ma je a gba gbe rara
Bobirin tin gbowo obe lo ja la o se ji se onrode wa reti abo wa
Ema je a tajo gbe sajo
Ori mi jo o eda mi jowo bi mob a roja tojo terun abo mi kodara
Ewu igbeyin de tan ara mi ehn
Aiye tin dori kodo ehn
Iku ben lo de arun un polowo bawo ni mura sile re ah
Janba se lori sirisi eh o tete ma fura ehn
Ore mi ma gbagbe ile unmunm
Eni to da wa o fe wa o fe wa ko fe se buburu
Oti silekun ona toro jan kariwo eru koni le gba be
Bi ole bi agbere ipani yan unko iro pipa eke inu ni bini
Iborisa pelu oso awo yen ni jan kariwo ehn
Onidi ku di o ni koja oya tete ye se owo re wo
Kolojo tode
Ona toro ko gbelese ehn keya tete gbo seti
Ano ja ma gbagbe ileuhmuhm
Okunrin a fa bo sile obirin roja a pada bo
Egbo eni rajo gbogbo se ni won fabo sile o
Ori mi jo o eda mi jowo bi mob a roja tojo terun abo mi kodara
Jowo jowo abo mi kodara
Mura lati fabo sile bo birin ti loja robe bo
Mura lati pade oba ajo oni dun ko ni ile ma re le
Opo eda ti gbadun oja adarin un won so ile aiye di wayi lo
Ko nipe tan odu aiye igba to ba tun gba tini opin
Egberun odun a to pe oremi ija fara lewu
O ti fi jesu yi se olugbala eni ba gbagbo yio ri iye
Eni ba gba gbo yio ri ye faiye e fun war i ye
Ku ati ye iseju kan lo la won iseju to kan ko seni to mo
Ona to toka si oun ni iye ona to toka sona iye
Jesu oluwa lona na ona toka sona iye
Igbala miran kosi ara to tu ju jesu to ku lori igi
Opo egbe ade egun oti kikan iya to je lori wa
Igbala un kigbe wa gba o igbala kigbe wa gba o
Iku jesu tiro gbogbo wani
Igbala re o ona iye eni ba gba gbo yio ri iye
Faiye e fun wari iye iku ati iye iseju kan lo la won
Iseju tokan ko seni to mo
Ona to toka si oun ni iye ona to toka sona iye
Jesu oluwa lona na ona toka sona iye
Igbala un kigbe wa gba o igbala kigbe wa gba o
Iku jesu tiro gbogbo wani