Aso Mi A Fufun Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2014
Lyrics
Aso Mi A Fufun - Tope Alabi
...
aso mi a funfun lau lau lau
aise dede mi akuro
ma fun fun lau
ese a pare ma si fun fun
a o wemi lawemo oo
bi egan owu
eni to wa ninu Jesu di eda titun
oun atijo, oti ko ja lo
a ti we wa kuro ninu ese wa
aso wa a funfun lau lau lau
karonu pi wa da
kako ese si me
kapara wa mo
laise dede wa
ki emi mimo ko joba lokan wa
angeli yo tori elese yi pada
(instruments)
ko si ese ti baba ko lewemo o
anu re doru
duro titi lai lai
elese ewa, a o fisimi sokan re
yio we gbogbo re
ki o si funfun lau lau
alanu lolorun,
o be elese wo bi omo ni
ko si b'ese se le po to
alaforiji ni
kiki da ko jawo
kaye re ko gba simi