Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2013

Lyrics

Oluwa iwo ni olorun mi

Ese olorun

Emi o gbe o ga mi yin oruko re

Baba baba mi ooo

Nitori to o se oun iyanu (o se oun iyanu)

Agbara talaka ko ku ninu ikan so

Iwo ni olorun mi ooo


Oluwa iwo ni olorun mi

Ese olorun e se olore

Emi o gbe o ga mi yin oruko re

Poripori ma popo

Nitori to o se oun iyanu (o se oun iyanu se)

Agbara talaka ko ku ninu ikan so


Eni mimo Isreali to se mi lore iwa l’aye oo

Ore awon ota ti koni fi eru re sile

Ose ore me le gbagbe ore ninu aiye mi

Mi o je gbagbe re olorun

O gbe mi leke emi yo yin o o baba

Baba baba oooo


Oluwa iwo ni olorun mi (aiye raye mo gbe o ga)

Emi o gbe o ga mi yin oruko re

Oba nla oba nla

Nitori to o she oun iyanu

Agbara talaka ko ku ninu ikan so


Iwo lo ba mi se to jo mi loju o baba

Olu fi ise ji to yi igbe aiye mi pada

Emi eni I ba wa le ma bere oun ti won se l’ode

O so mi di pataki o se o baba rere

Ibi o ba mi de yi mo ma dupe o eh

To ba je ta dura tabi a we emi o ye rara

Bo de je ti ojo ori mo kere ni yen o jojo

O fi anu gbe mi ro gbe mi joko l’arin awon oba

Momo pe wa baba


Oluwa iwo ni olorun mi (o se o baba mi o)

Emi o gbe o ga mi yin oruko re (o l’ore mi ni o)

Nitori to o se oun iyanu (alagbara ni shiloh)

Agbara talaka ko ku ninu ikan so


Ni ti ise owo mi

Mi o to lati se aanu fun

Ko si oun ti mo ni tole ra gbogbo oun ti ofi tami lore

Oni bu ore mi ole yin o tan titi aiyeraiye

Oba to fi mi ya won lenu o mo ki yin


A o se baba mi ose emi kole yin o tan o

Okuta ti awon mole ko sile

Di pataki igun ile

Ise oluwa leyi o

O se o jesu o seun

Ao se baba mi ose emi kole yin o tan o

Okuta ti awon mole ko sile

Di Pataki igun ile

Ese oluwa leyi o

O se o jesu o seun


You are the lord and that is your name

You will never share your glory with any man

Because you are the lord and that is your name

You will never share your glory with any body


Eran ko to se bi olo layi ju odi lailai kan gba

A gbin yan ju fe se bi jesu oun lari ooo

Omo oba ogo ko le se bi baba eni kan

Oro gan ji gan olu orun o oba nla

Ko se fi se a ka we eni ke ni l’aye lorun

O be le se wo bi omo eleje pese re

Oba to n ka gbogbo aiye laya ti aiye o de le ka l’aya lailai

Royal Majesty oba ti iku o le kan lailai

Obi gbogbo aiye baba ati mama everybody wa ni

Olorun to ju awon aare lo mo hun se iba ooo

Eru ipe kun oni she ibi baba mi ni

Ayo igbeyin oni se rere baba


You are whiter than snow olorun mimo

Olorun ibeere ati opin oun gbogbo


You will never share your glory with anybody

Ani iwo ni olorun ko si eni to le ba o pin ogo re

You will never share your glory with any man

Oba yi o mo ri eya ga o ra

You will never share you glory with any man

Afi yi wu aba si eyi fo eyi goro

You will never share your glory with any man

Chuwkwu na obu su oye dike oye zo

You will never share your glory with any man

Wu ye o be wu oye obiora ni o yi a o ti se wo

You will never share your glory with any man

Ke de wu ban jigi suna ka kanna

You will never share your glory with any man

Ke de wu ban jigi sun aka kina iwo lolorun se

You will never share your glory with any man

Eh you will never share your glory with anybody

You will never share your glory with any man


Olowo ori mi o

Olowo ori mi o oba mi aditu

Olorun mi

Adake reti aiye oooo

A ka owo le ro wo ise awon omo eniyan

Oba mi a dajo ma fi ti oun nikan se

Olowo ori mi ooo

Olowo ori mi ooo oba mi aditu

Olorun mii

Olorun ti ga ee lawa ke pe oo

Olorun to bukun u (eyin l’awa ke bo)

Olorun to jin to fe (eyin l’awa ke bo)

Eyin sha ni olorun ti ko lo ga oo (eyin l’awa ke bo)

Eyin l’olorun ti ko ni ikeji (eyin l’awa ke bo)

Olorun olodumare oo (eyin l’awa ke bo)


Ogo ni fun baba

Ogo ni fun omo

Ogo ni fun olorun emi mimo

Baba gba ogo o

Ogo ni fun baba

Ogo ni fun omo

Ogo ni fun olorun emi mimo

Baba gba ogo

Olorun ibere olorun opin

Ara nla bowo ija nla

Ogba gba tin gbagbara l’owo iku ooo

Mo oo se iba re oo

Ogo ni fun baba

Ogo ni fun omo

Ogo ni fun olorun emi mimo

Baba gba ogo oo

Iwo nikan le mi o ma bo

Iwo nikan le mi o ma sin

Oba ti o le ku oba ti o le te o

Iwo nikan lemi o ma bo

Iwo nikan le mi o ma bo

Iwo nikan le mi o ma sin

Oba ti o le ku

Oba ti o le te o

Iwo nikan lemi o ma bo


Iba re Jesu mi iba re

Iba re mi o ni fi ori bale fun orisa kan kan

Ibare Jesu mi iba re

Ibare mi o ni fi ori bale fun orisa kan kan

Iwo lo to

Lo to se iba fun o

O su ba re mi o je fi ori bale fun orisa kan kan

Mowa yi ka otun

Mo tu yi ka osi

Mo pa robo robo tani ti nba se be fun bi ko ba se iwo

Iwo nikan l’oto be

Iba re Jesu mi iba re

Iba re mi o ni fi ori bale fun orisa kan kan


Akii ki tan Olodumare

Akii ki tan eleru niyin

Akii ki tan oba to sanu mi ooo

Arugbo ojo adagba ma paro oye

Akii ki tan olodumare

Akii ki tan eleru niyin

Akii ki tan oba to n s’anu eni

Arugbo ojo adagba ma paro oye

Ape pe tan ojogban to ju ogban ori aiye gbogbo lo

Oba aditu to je ki oyun ko ma won ninu aboyun

O ni a bi mi sha ju awon oke olodu omo are

Oloruko pupo a ole ki o tan o baba mi

Akii ki tan olodumare

Akii ki tan eleru niyin

Akii ki tan oba to n s’anu eni

Arugbo ojo adagba ma paro oye


Mo ni kabiyesi re o baba

Kabiyesi re o omo

Kabiyesi re o emi mimo ido bale la mi k’oba

Kabiyesi re o baba

Kabiyesi re o omo

Kabiyesi re o emi mimo ido bale la mi k’oba

Mo dupe oru mi o ko aso

Ori mi o ko gele

Ese mi o ko bata l’aye ido bale ni mo wa o baba

O o dupe ori re o daru

Oun be l’aye aiye re o ko a tun se

Ti emi bawa ireti n be oye ki o yin abi ko ye

Ninu ope lo fi da wasi


Kabiyesi re o baba

Kabiyesi re o omo

Kabiyesi re o emi mimo ido bale la hun k’oba

Ido bale la mi k’oba idobale la mi k’oba

Oya yi ka otun ko yi ka osi ko pa ru gu rugu

I do bale la mi ki oba


Oba awa ma ni JESU

Oba awa ma ni

Oba awa ma ni JESU

Oba awa ma ni

Awo ma ni oba imiran a fi ori bale fun ooo

Oba awa ma ni

Oba laye lo run ti gbogbo aiye pari wo

Oba awa ma ni

Oba ni lo ri aiye mi oba ni

Oba ni lori aiye re oba ni

Abo to ni pan oun lon fi bo mi o oba ni

Ohun ni o je ki ipa aiye ka mi tile tile oba ni

To ba se pe oba aiye gbogbo wan i a hun so owo ori wa l’aye

Ni ti nu aiye oba sun saju ilu re

Oun ni kan l’oba tin ki sun ti ki tohun gbe oo oba ni

Ani l’aye bi ao fi owo iye bi ye ra abo fun arawa ni

Awon bi aja bi olode ti o gboju ninu aiye oo

Ode o le gbo ju titi ko yin ibon mo ogun aiye wa

Oun ni kan loba ti je emi ni mase beru oba ni


Alapa mo alase tan

Oba ni lo ri aiye mi oba ni

Oba ni lori aiye re oba ni

Abo to ni pan oun lon fi bo mi o oba ni

Oun ni o je ki ipa aiye ka mi tile tile oba ni


Agbara ti ko le baje

Agbara ti ko le sa

Agbara ti kin e pin o

Agbara olorun ni

Agbara ti ko le baje

Agbara ti ko le sa

Agbara ti kin e pin o

Agbara olorun ni


Ipa to fi ewe fun igi oo

Okun lo fi ododo fun oke

Emi to fi imole fun san mo

Owo re lo fi yan ona mi


Agbara ti ko le baje

Agbara ti ko le saa

Agbara ti kin e pin oo

Agbara olorun ni


Iwo la o ma bo ani iwo la o ma bo

Olorun to gbe mi gba mo ki o motun ki o (iwo la o ma bo)

Agbara re ma po

Agbara re ma po

Oun re lo fa igi kedari ya

Agbara re ma po

Ogo re ma le wa to o (ogo re ma l’ewa o)

oba ti gbogbo angeli ke mimo mimo si

Ogo re ma le wa to

Ife re si wa ga

Ife re si wa po

Oba to ku fun awa else ka le ye (Ife re si wa po)

Oma dara si wa o

Omo sun won si wa o

Iba se pe o sami ese talo le duro

O dara si wa o

Iwo la o ma bo

Ani Iwo lo ma bo

Olorun to gbe mi ga mo ki o mo tun ki o

Agbara re ma po

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status