Wa Gbadura Mi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Wa gbadura mi wa gbadura mi
Bi le aliye se lo yeye ko ma ye mi to
Bi mo ba kun le bi mo ba gbadura wa gbadura mi
Wa dariji mi wa dariji mi
Ninu ese mo je ti mo rin tin mo mu laiye
To ba ro tese mi o ni gbadura mi wa dariji mi
Wa sanu fun mi wa sanu fun mi
Mo re le alawo mo re le oni segun ko ni yanju
Woni kin wa loni kin wa lola ko wa sanu fun mi
F’ayo kun nu mi f’ayo kun mi
Eleduwa to da aiye to da orun
Alayo mo fe je nile ayo mi
F’ayo kun nu mi
Ki re je temi ki re je temi
Awon to ti ro mi pin ti won sope mi o le je unkan laye
Wa yawon lenu kan ri re ayomi
Ki re je temi
Olorun ton gbadura gbadura mi
Olorun gbo adura ko gbo adura mi
Olorun ton gbadura gbadura mi
Olorun gbo adura ko gbo adura mi
Olorun ton gbadura gbadura mi
Olorun gbo adura ko gbo adura mi
Olorun ton gbadura gbadura mi
Olorun gbo adura ko gbo adura mi
Olorun ton gbadura gbadura mi
Olorun gbo adura ko gbo adura mi