Loading...

Download
  • Genre:Hip Hop & Rap
  • Year of Release:2024

Lyrics

ONÍṢẸ́ by DOKITA OLAMIDE


Ìwọ ló n'ṣẹ́

Ìwọ ló ń ṣiṣẹ́

Eleduwa tó ń darí ayé mi ò

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ 3x


Olúwa ń sọ di tálákà

Ó sì ń sọ di ọ̀lọ́rọ̀

Olúwa ló ń gbé' kan sókè

Ó sì ń gbé ikan wá 'lẹ̀

Kabiyesi tó ń gbé'lé ayé mi r'òkè

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ 2x



Ìwọ ló n'ṣẹ́

Ìwọ ló ń ṣiṣẹ́

Eleduwa tó ń darí ayé mi ò

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ



Ìwọ ni olúwa

Èyí ni orúkọ Rẹ

Àwọn kan ń sọ wípé ó ti tán

Bàbá mi sọ wípé rárá

Kabiyesi f'ọba tó ni gbogbo ògo o

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ



Ìwọ ló n'ṣẹ́

Ìwọ ló ń ṣiṣẹ́

Eleduwa tó ń darí ayé mi ò

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ



Ìgbà mi kì bá ti tán tipẹ́

Opelope Olúwa wa

Àsìkò mi kì bá ti parẹ́,

Bí kò bá sí olúwa,

Ibi láyé ń retí,

Ìwọ ló fi ire rọ́pò,

Jésù tó dojú t' ẹlẹ́gàn ayé mi ò,

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ.


Ìwọ ló n'ṣẹ́

Ìwọ ló ń ṣiṣẹ́

Eleduwa tó ń darí ayé mi ò

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ 2x


Elédùà tó ń darí ayé mi ò,

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ



Elédùà tó ń darí ayé mi ò,

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ



Elédùà tó ń darí ayé mi ò,

Jàre máa bá'ṣẹ́ Rẹ lọ

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status