O maa dara Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
Eni to jobe gure,eyi to san de igbonwo o
Eni to jobe gure pelu eba ti ko leran
O maa dara, gbogbo re lo maa dara
Omaa dara, a dara lojokan.
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
Eni to jobe gure,eyi to san de igbonwo o
Eni to jobe gure pelu eba ti ko leran
O maa dara, gbogbo re lo maa dara
Omaa dara, a dara lojokan.
Ore ma parare, mamase rare lese
O maa dara, a dara lojo kan
Gbogbo ohun ti koto, gbogbo re
Lo maa seku nile aye
O maa dara a dara lojo kan
Ore ma parare, mamase rare lese so gbo
O maa dara, a dara lojo kan
Gbogbo ohun ti koto, gbogbo re
Lo maa seku nile aye nbi
O maa dara a dara lojo kan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
Eni to jobe gure,eyi to san de igbonwo o
Eni to jobe gure pelu eba ti ko leran
O maa dara, gbogbo re lo maa dara
Omaa dara, a dara lojokan.
Oorile be tabonile n yo lenu o
O maa dara, a dara lojo kan
Ooraso wo, tabi ohun waso to ya nile aye
O maa dara, a dara lojo kan
Oorile be tabonile n yo lenu oo
O maa dara, a dara lojo kan
Ooraso wo, tabi ohun waso to ya
O maa dara, a dara lojo kan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
Eni to jobe gure,eyi to san de igbonwo o
Eni to jobe gure pelu eba ti ko leran
O maa dara, gbogbo re lo maa dara
Omaa dara, a dara lojokan.
Jowo mase kanju, ore fori tii o
O maa dara, a dara lojo kan
Tori nile aye ohun gbogbo lakoko wa fun
O maa dara a dara lojo kan
Ape koto jeun, won kiije ibaje o
O maa dara, a dara lojo kan
Jowo mase kanju, ore fori tii o
O maa dara, a dara lojo kan
Tori nile aye ohun gbogbo lakoko wa fun
O maa dara a dara lojo kan
Ape koto jeun, won ni kiije ibaje o
O maa dara, a dara lojo kan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
Eni to jobe gure,eyi to san de igbonwo o
Eni to jobe gure pelu eba ti ko leran
O maa dara, gbogbo re lo maa dara
Omaa dara, a dara lojokan.
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
O maa dara, okuku maa dara
Omaa dara a dara lojokan
Eni to jobe gure,eyi to san de igbonwo o
Eni to jobe gure pelu eba ti ko leran
O maa dara, gbogbo re lo maa dara
Omaa dara, a dara lojokan