Oju Ko Tiri Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2019
Lyrics
Oju Ko Tiri - BUKOLA BEKES
...
oju ko iri
eti ko Igbo
oun to Jesu fe se
ninu aye mi
ise agbara, ise iyanu
ti o ya raye lenu
ni Jesu mi yo se... (2ce)
awon to duro de Oluwa
won yio dabi Oke sion
ti a ko le si ni idi sugbon ti o
durooooo... lae lae..
CHORUS(2x)
Baba mi atolorun mi
funmi ni ranwa re
kinle roka gbogbo aye...
Lola oru...ko Jesu
CHORUS(2x)
Masise lo mase rope
ako gbo adura edun re
ojo isinmi mbo Kan Kan
sa roju duro mase ku.
duro roju duro masekun
duro duro sa roju duro masekun(2x)
Agbara, Agbara Agbara
Olorun mi kole dibaje o lae lae(2x)
Agbara to laju afoju ...Yes
to ji Lazaru dide.... Yes
to so agan do lomo.... Yes
to wo birin Orisun eje .... Yes
owa sowa di alagbara ...... Yes
to fa igi kedari Ya..... Yes
Agbara Olorun mi kole dibaje o lae lae.
Agbara, Agbara o
Agbara Olorun mi kole dibaje o lae lae.
Baba eku ise ooo.
Baba eku ise ooo.
Ise re kin dibaje ooooo.