Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2023

Lyrics

Iwo Lapata

To ga ju gbogbo oke lo

Iwo Lapata

To duro gboingboin

Iwo Lapata o

Ti mo feyin ti o

Jesu

Iwo Lapata o

Ti mo simi le


Eyin eniyan gbogbo

Eje ki agbe oluwa ga

Ohun li Apata wa

Olugbala wa

Agbara wa

Asa wa

Aabo wa

Igbala wa

Ile-iso giga wa

Oluwa mbe olubukun si li Apata wa


Iwo Lapata

To ga ju gbogbo oke lo

Iwo Lapata

To duro gboingboin

Eni ba gbekele o

Eni ba gbekele o

Yio dabi oke sioni

Eni ba gbekele o

Awa duro sinsin

Jesu

Iwo Lapata

Ti mo feyin ti o

Jesu

Iwo Lapata

Ti mo simi le


Nwon wo o

Imole si mo won

oju ko si ti won

Nitori

Iwo Lapata

Ti mo gb'oju le o

Nitori o

Iwo Lapata

Ti mo gb'oju le o


Iwo

Iwo Lapata

To ga ju gbogbo oke lo

Iwo Iwo

Iwo Lapata

To duro gboingboin

Eni to ba gbekele o

Eni ba gbekele o

Yio dabi oke sioni

Eni ba gbekele o

A duro sinsin

Iwo Lapata

Ti mo feyin ti

Ti mo feyin ti o

Jesu Atosimile

Iwo Lapata

Ti mo simi le


Eni to ba

Saferi o

yio si ri o

Nitori

Iwo Lapata

Mo fi gbogbo okan mi wa o

Nitori o

Iwo Lapata

Mo fi gbogbo okan mi wa o


Iwo

Iwo Lapata

To ga ju gbogbo oke lo

E ga E ga

Iwo Lapata

To duro gboingboin

Eni to ba gbekele o

Eni ba gbekele o

Yio dabi oke sioni

Eni ba gbekele o

Awa duro

A duro sinsin

Jesu

Iwo Lapata

Ti mo feyin ti o

Jesu Atogbojule

Iwo Lapata

Ti mo simi le


E ko gbogbo

Ani yan yin le

Ohun lo nse itoju wa

Nitori

Iwo Lapata

To le toju mi

Nitori o

Iwo Lapata

To le toju mi


Iwo Lapata

E ga ju gbogbo oke lo

To ga ju gbogbo oke lo

Iwo Lapata

To wa duro gboingboin

To duro gboingboin

Eni to ba gbekele

Eni ba gbekele o

Yio dabi oke sioni

Yio dabi oke sioni

Eni ba gbekele

Eni ba gbekele o

Awa duro sinsin

A duro sinsin

Iwo Lapata

Ti mo feyin ti

Ti mo feyin ti o

Iwo Lapata

Ti mo wa simi le

Ti mo simi le


Eni

Ti o ba sa pe oruko oluwa

Li a o gbala

Nitori

Iwo Lapata

To le gbami la

Iwo Lapata

To le gbami la


Eyin li Apata

Ti A simi le

Iwo Lapata

Ti o le gbami la


Nitori pe

E le gba wa la

Iwo Lapata

To le gbami la


Gbogbo eni to ba wa o

Yio si ri o

Iwo Lapata

To le gbami la


Gbogbo eni to ba gbokan le o

Yio si ri o

Iwo Lapata

To le gbami la


Gbogbo eni to ba pe oruko re

Li a o gbala

Iwo Lapata

To le gbami la


Gbogbo eni to ba sa to o

Yio ye

Iwo Lapata

To le gbami la


Jesu

Iwo Lapata

To le gbami la


Iwo Li Apata wa

Iwo li Apata wa

Ti A le pe nigba gbogbo

Iwo Lapata

To le gbami la

Iwo Lapata

To le gbami la

Iwo Lapata

To le gbami la

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status