Oluwa Is Involved Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2017
Lyrics
Oluwa Is Involved - Oyinkanade
...
Ahi... eh
Yabayoshaya ya... Ah eh
Selemama... Elimama jakura
Elijah... mo ti r'irapada
Awõn malaika ti n be l'orun Yeh
B'opolo se n yan l'oju elegusi ko ku le fi jeun
Gb'oro mi ro Baba, k'aye ma ma sun mi je o See, everywhere I dey go, people dey hail my name now
I no dey walk alone like my Liverpool o
Mo ti r'irapada
Iyanu ti sele
Ôkan mi ti bale, anywhere we try chopu gala
Mo ti r'irapada
Iyanu ti sele
Ôkan mi ti bale, anywhere we try chopu gala
Oluwa... Oluwa... Oluwa is involved
Oluwa... Oluwa... Chineke is involved o
Oluwa... Oluwa... Oluwa is involved
Is involved
Oluwa... Oluwa... Oluwa is involved
Oluwa... Oluwa... Chineke is involved o
Oluwa... Oluwa... Oluwa is involved
Oluwa is involved
Chineke is involved
Mo gb'oun s'oke s'onile kewu
Mo s'eri mo ta f'alaafin orun
Ijirale, ijiramisauda
Adaba ti ko le fi, omo araye lo fi da
Awon asebi n binu wa 'tori iya won o b'iru wa
Oyinkanade pelu Q-Dot, e o le m'asiri wa
'Tori ewure o le ga to malu, LASTMA o le m'omo yahoo
Ijira yeh, Ijira malaika seribumi
Oluwa... Oluwa... Oluwa is involved
Oluwa... Oluwa... Chineke is involved o
Oluwa... Oluwa... Oluwa is involved
Is Involved
Oluwa... Oluwa... Oluwa is involved
Oluwa... Oluwa... Chineke is involved o
Oluwa... Oluwa... Oluwa is involved
Oluwa is involved
Chineke is involved
Oh le le le le (Eh le le le le)
Sele, Oh le le le le (Eh le le le le)
Sele, Oh le le le le o (Eh le le le le)
Ah, Oh le le le le le le (Eh le le le le)
Oba mi, atobajaye o
Iwo lo gbe mi leke aronipin o
Iwo lo n fun mi l'oro so larin egbe o Baba
Oya mo ki o pe yabayabosha baba
Eheheheh aah