Fi iyin fun Jesu Olurapada Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Fi iyin fun Jesu Olurapada - Hibeekay
...
#
#F iyin fun jesu, olurapada wa,
ki aye k’okiki ife re nla;
Fi iyin fun! Eyin angeli ologo ,
Fola at’ogo fun oruko re,
B’ola’ agutan, jesu yo to Omo re
L’apa re l’o ngbe won le l’olojojo
Eyin eniyan mimo ti ngbe’ oke sion
Fi iyin fun pelu Orin ayo .
#
#
# F iyin fun jesu, olurapada wa,
Fun wa, o t’ eje re sile, o ku
O ni apala, ati reti ‘gbala wa,
Yin jesu ti a kan m‘ agbelebu;
Olugbala t’o f‘ara da irora nla
Ti a fi ade egunde Lori
Eniti a pa nitori awa eda
Oba ogo njoba titi laelae.
#
#beat.................,,,,,,,..........................................,
# F iyin fun jesu, olurapada wa,
ki ariwo iyin gba Orun kan
jesu oluwa njoba lae ati laelae,
Se l,oba gbogb’ eyin alagbara.
A segun Iku; fi ayo royin na ka
I segun re ha da, isa oku?
Jesu ye ko tun si whala fun wa mo
‘Tori o’ lagbara Lati gbala.
AMEN