Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2023

Lyrics

Oyigiyigi Baba

Oyigiyigi Baba

Mowa dupẹ o

Fun ore rẹ lori aye wa o


Oyigiyigi Baba

Oyigiyigi Baba

Mowa dupẹ o

Fun ore rẹ lori aye wa o


Baba mimọ o, mowa sọpẹ

Mo fi iyin forukọ nla rẹ

To r'ore rẹ, opọ o'tobi

Ninu aye wa o


Baba mimọ o, mowa sọpẹ

Mo fi iyin forukọ nla rẹ

To r'ore rẹ, opọ o'tobi

Ninu aye wa o


Oyigiyigi Baba

Oyigiyigi Baba

Mowa dupẹ o

Fun ore rẹ lori aye wa o


Oyigiyigi Baba

Oyigiyigi Baba

Mowa dupẹ o

Fun ore rẹ lori aye wa o


Baba mimọ mowa dupẹ

(Baba mimọ mowa dupẹ)


Baba mimọ mowa dupẹ

(Baba mimọ mowa dupẹ)


Lori aye wa mowa dupẹ

(Baba mimọ mowa dupẹ)


Baba mimọ mowa dupẹ

(Baba mimọ mowa dupẹ)


Lori ẹbi wa mowa dupẹ

(Baba mimọ mowa dupẹ)


Baba mimọ mowa dupẹ

(Baba mimọ mowa dupẹ)


Baba mimọ mowa dupẹ

(Baba mimọ mowa dupẹ)


Lori ile wa (mo wa dupẹ)

Lori isẹ wa (mo wa dupẹ)

Lori ẹbi wa (mo wa dupẹ)

Lori aye (mo wa dupẹ)

Lori ọmọ wa (mo wa dupẹ)

Lori ile wa o (mo wa dupẹ)


Ma dupẹ o

Lọwọ ọlọrun o

To dami si ma dupẹ o


Ma dupẹ o

Lọwọ ọlọrun o

To dami si ma dupẹ o


Ta lodabi rẹ

Ni gbogbo aye

Ko sẹni to ga to tun dabi rẹ


Ta lodabi rẹ

Ni gbogbo aye o

Ko sẹni to ga to tun dabi rẹ


Talo dabi ọlọrun mi

Ko si o, kosi o


Talo dabi ọlọrun mi

Ko si o, kosi o


Talo dabi ọlọrun mi

Ko si o, kosi o


Talo dabi ọlọrun mi

Ko si o, kosi o


Talo dabi ọlọrun mi

Ko si o, kosi o

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status