Odun Yi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2017
Lyrics
[ti:Biyi Samuel- Odun Yi]
Odun odun yii adun
Odun odun yii ayabo
A gbohun rere se o
L’ola oluwa
Odun odun yii adun
Odun odun yii ayabo
A gbohun rere se o
L’ola oluwa
Iyi Alafia to pe ye
Fe mi ati iwo
Itelorun *** adura fun wa
Ifokanbale titi dojo ale
Fe mi ati iwo
Ki odun tuntun fi won wipe gbogbo odun je adun
The lord’s goodness mercy and favour
That’s all we pray for
Jeki ayo inu okan wa ko ju
Ta teyin wa lo
Odun yii ooo
Odun odun yii adun
Odun odun yii ayabo
A gbohun rere se o
L’ola oluwa
Odun odun yii adun
Odun odun yii ayabo
A gbohun rere se o
L’ola oluwa
Peregede la oye ooo
Peregede la oye ee
Peregede la oye ooo… tebi tara
Peregede la oye ee
Tori naa
Peregede la oye ooo
Peregede la oye ee
La lai ku
La lai beru
La lai banuje
Peregede la oye
Peregede la oye ee
Aniku, owo ati arun segun
Lo ma je
Lo lo
Maje je tiwa
Odun yii ooo
Odun odun yii adun
Odun odun yii ayabo
A gbohun rere se o
L’ola oluwa
Odun odun yii adun
Odun odun yii ayabo
A gbohun rere se o
L’ola oluwa
Odun yii ahh…
Odun yi oo
Abi re fun dede wa
Odun yi oo
Abi re fun dede wa
Ahhh
Abi re
A bola
A bowo
A bomo
A ba lafia
A ba lafia fun fun dede wa
Odun yi oo
Abi re fun dede wa
Because I believe
Mo ma ri ba ti se ni odun yii
Odun yii ma lola lola
Ehh ***
Ose
Eh moma yo mo ma yo
If you know me before know before
You no go know me again
Opon ti sun ati sun si waju
Odun yi oo
Abi re fun dede wa
Ka ma sajoyo mayo
Odun yi a ma ribatise
E sa amin se amin e
Odun yi oo
Abi re fun dede wa
Odun yi oo
Abi re fun dede wa
Odun yi oo
Abi re fun dede wa