Mo Dupe Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Mo Dupe - Tope Emmanuel
...
Eledumare mo dupe dupe
O se olugbeja mi
Iwo loogba ka'ye mi o ri
Bi ota mi ti fe ko ri.
L'oju amokoko bi ki le o d'amo ni
L'oju amoniseni bi ki nr'ajo
Kin ma pada de 'le mo
Sugbon Oluwa gbe iwo re soke
O ramipada o gba mi lowo ewu gbogbo
Atinileyin mi o baba omo
Eyan o le se yi o
A fi Iwo
Mo dupe baba
Eledumare mo dupe dupe
O se olugbeja mi
Iwo loogba ka'ye mi o ri
Bi ota mi ti fe ko ri.
Eledumare mi oooooo
Eledumare mo dupe dupe
O se olugbeja mi
Iwo loogba ka'ye mi o ri
Bi ota mi ti fe ko ri.
/Bridge /
Baba ti ki f'omo sere
Abiyamo to ponmi ti ko je njabo
Kiki da olanla ni o
Alafin kiki ogo
Kabiyesi mo f'ori bale mo wa dupe ore
Kabiyesi mo f'ori bale mo wa dupe ore
Baba ti ki f'omo sere
Abiyamo to ponmi ti ko je njabo
Kiki da olanla o se
Alafin kiki ogo
Kabiyesi mo f'ori bale mo wa dupe ore
Kabiyesi mo f'ori bale mo wa dupe ore
Emi mo riri re / Olore e se
Emi mo riri re edumare mi /Olore e se
Mo r'owo re, mo rise re laye mi baba
/Olore e se
Mo dupe, mo dupe, mo dupe baba
/Olore e se
Akiri sore asore Kiri /Olore e se
Oro mi t'ope o tun ju ope lol /Olore e se
Haaaa!
Mo dupe, mo dupe, mo dupe, mo dupe Oluwa! eeeeee ba!
Emiiii mo riri edumare mi / Olore e se
Atinileyin k'oju ma ti ni /Olore e se