Kristeni Elegbin Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Kristeni Elegbin - Evang. Tope Olutokun
...
iwo Gangan Lori bawi Kristen eligbin
ewo egin ni nu ako ijo mi
ewure Larin aguntan
jade lo kamase kao mowon mo
mo korin ko nigba kan pee okan elegbin
Larin eniyan Mimo
eniyan la wa ninu ijo
ko si je olori alagbere
eniyan le WA ninu ijo ko si je Baba Yan ale Yan ale
osa elegbin ole ma tako ebun aye won
akorin elegbin ole ma tako ebun aye wa
wontu le ma fedefo sungbon aye won kun fun egbin
ifarahan oluwa ninu aye eniyan
nigba mi ran oo
ko ni se pelu nkan ta fi oju re
eniyan le po ninu ijo,abi ki pastor kora Moto pupo
ole ma si owo olorun nibe
okan so didara olorun lasan
pastor Oni ijekuje ranti Ile ti Oti tuka
igbeyawo ti Oti tuka
opor eniyan ti Oti jalole
Ohun rere Sonu
ako isura lagbalo
nigbati eniyan sunlo
awon to ye koja ati ko won lagbara lo
awon to ye ko so ijo gbo gbo won nigbe ninu igbekun
eyi to buru Jo lo ni awon ti ogbe ohun elo oluwa
owo won kun fun eje,aye won kun fun egbin
bi iro pipa,bi jibiti,agbere Niko ko full stop ninu ijo
owo oluwa dakun ra aye wa pada
tete se o
tete se olu Orun o Baba mimo womipale ko ti mi mo
Pepe oluwa to to di egbin ninu aye mi
Baba mimo womipale ko tu mimo
Sebi iwo ni amokoko aye mi 3x
oluwa mo mi bi o se Fe
ti o ba mo mi egbin a di irira
ti o ba mo mi ayemi alodi si ese
ti o ba mo mi ma gbe igbe aye iwa mimo
ti o ba mo mi ma wu lo fun ogo re Baba
Baba mimo womipale ko tun mi mo