Osan (Orange) Lyrics
- Genre:Afrobeat
- Year of Release:2023
This song is not currently available in your region.
Lyrics
Jerryson production
Interlude
Ibi a gbinsan si latinka
Ofe kajo nibi too tida, koma seese
Ma yanbo nibi toosesi o
Kole possibe, kole seese
Ibi a gbinsan si latinka
Ofe kajo nibi too tida, koma seese
Ma yanbo nibi toosesi
Kole possibe, kole seese
Ibi ta moyan si lati nyan
O mada ka sunmo eyan to mo
Iyi ta ni foun
Olowo toriwa naa lanri
A m'awon ton fewa
Awon lama nji sadua fun, ta tunma se robbana
Sungbon awon tonjeun toko tio sope, e bamire
Awa naa o ni ranti ati sope
A gbabi ire
Ibi a gbinsan si latinka
Ofe kajo nibi too tida, koma seese
Ma yanbo nibi toosesi
Kole possibe, kole seese
Eni tio funwa niyawo fe
Koma pewa lana
Eni toòferi nigba tonwa
Iranlowo e
Toba digba toma wulo fun e
Somale pe funyen?
Ojeya wulo nigba toni, kotete se loda
Bofe yanbo nibi toosesi
Kole seese, kole possible
Ibi a gbinsan si latinka
Ofe kajo nibi too tida, koma seese
Ma yanbo nibi toosesi
Kole possibe, kole seese
Mashaallah
Ibi a forosi ni eje a ba
Mase adeun boolese
Koye koribe
Eyan to npon e le tetese
Oun tobaye
Tori bopada niun toòlefun
Awon kan tunwa
Tiwon maro pewo naa lose
Afi to baso o
Eeya tete wulo nigba teni, anfani loda o
Keye ma yanbo nibi teo sesi
Kole possibe, kole seese
Ibi a gbinsan si latinka
Ofe kajo nibi too tida, koma seese
Ma yanbo nibi toosesi
Kole possibe, kole seese
Base nso pafe jola
K'olohun bawa se
A nbelohun tolese
Lojojumo aye
Ari motor tafe
Ati iru ile tafe
Umura lododun
Atarafa alalode
Anri bi potiya
Lai lowo tolese
Kini idaniloju
Tafi life kope, igbagbo
Iruyin tani, iruyin tani
Lonje kamo polohun
Oba ti bawa se
Eni wu olohun loma ran
Oti bamise, mo loloju aanu
Mofi lolohun oba time
Momo omo baba ado
Adeleke ado, alayide nmoni
Mowa nfolayanka
Alhaji abdullahi
Tolohun funmi tan, ayinde
Iruyin tanis, iruyin tani
Lonje kamo polohun
Oba ti bawa se
Mashaallah
Mo loun timofe Allah
Timofe o bamise
Anikan sha loran
Toran pe kolose
Kotodi poma se
Koma bolayen je
Tobadi potise
Koma polayen re
Adeleke ado, onjise oju aanu
Gbogbo oun tinba tife
Toba wa nikapa re
Alayinde mase gene
Iruyin tani, iruyin tani
Lonje kamo polohun
Oba ti bawa se
Alfa lomo baba ado
Abdullahi ado, tonrise agbara je
To koja kekere
Kii wuwa boseto, tonpe ni motomoto
Erin lotun marin, kii foju lile se
L'osogbo boseto
E beere baba ado
Baba fi were boju, alayinde yoju
Olohun, koma gbota láàyè
Laye adeleke ado
Iruyin tanis, iruyin tani
Lonje kamo polohun
Oba ti bawa se
Eba jentete ya ibikan na
Kinma f'oju kan se aaye mi
Totun tosi lale fi yán
Awon agbada to dùùnri
Tiwaju teyin ni moma ngbe
Ninu okan akan-o olayode
Olatunde hajji saheed
Oko tayelolu amina
Alase olateed olaoluwa
Enterprises to gbayi mani
K'olohun joo ko bamiso
Olatunde di billionaire
Tori gbogbo awa tanfe, adua wa manipe
Olohun o nije koku
Adua o nije korun
Risise koni je Koran
Aso iyi e konisha rara
Oju e o niwon legbe
Itesiwaju lori dida oruko (Alhaji saheed olayode) c.e.o olateed olaoluwa enterprises
Timotimo e ni lati kekere
Oun gan lolohun onije koku
Adua o nije korun
Risise koni je Koran
Aso iyi e konisha rara
Oju e o niwon legbe
Ojagun tun ogun ja ajagun ti kiisa
Oja ogun togun ja ajagun
Ageshin tun eshin gun tikosu ri ngba kan
Agun eshin tun eshin gun eniire
Alhaji ayinde qomarudini alafe
Owo toti na ole lounka lorimi
Ayo lofita asise debe a maje
Agbega lo nnasi omadebi ayo odaju
Onilenlaaaa o (sure) onilenla o le kabamo lorimi
Anadanu o mani wobe momore o
Ojagun tun ogun ja ajagun ti kiisa
Oja ogun togun ja ajagun
Ageshin tun eshin gun tikosu ri ngba kan
Agun eshin tun eshin gun entire
Abbey de don nilu germany longbe ooo
Abbey de don nilu germany longbe
Gbogbo agbaye nonti dae mo l'akoni
Onilenla qomarudini alafe
T'alabosi bati gbe iranu ejo de
Onilenla bami lewon ju sigboro
Ibi tondun none fikoro si shoye ha
Ojagun tun ogun ja ajagun ti kiisa
Oja ogun togun ja ajagun
Ageshin tun eshin gun tikosu ri ngba kan
Agun eshin tun eshin gun entire
Ahun nio wulo f'ebi atara
Ahun nio wulo fara odede o
Oko kilera te o legun o
Abi ile kileko te o legbe
Adugbo wo lewa teo lerin
Iwa kilewu tio segbo, eeri cooler
Rilwanu nyan lagbegbe bi oba ni
Aremu nyan lagbegbe bi oba ni
Rilwanu nyan lagbegbe bi oba ni
Itesiwaju lori dida oruko alhaji ridwan cooler (olori odo of ijora kingdom)
Rilwanu nyan lagbegbe bi oba ni
Olawale nyan lagbegbe bi oba ni
Rilwanu nyan lagbegbe bi oba ni
Itesiwaju lori dida oruko alhaji ridwan cooler (olori odo of ijora kingdom)
Rilwanu nyan lagbegbe bi oba Aremu nyan lagbegbe bi oba ni
Rilwanu nyan lagbegbe bi oba ni
Konibaje fanon eyan ton obese
Lalai gborin ejire lojumo
Koniye danu fawon eyan ton obese
Lalai gborin ejire lojumo
Alhaji larry tonbe l'america
Olanrewaju lawal oko bunmi madina
Baba olajide adio maliki
Alhaji mutual ololufe daada
Itesiwaju lori dida oruko awon fans ati awon alajosepo
Konibaje fanon eyan ton obese
Lalai gborin ejire lojumo
Koniye danu fawon eyan ton obese
Lalai gborin ejire lojumo
Konibaje fanon eyan ton obese
Lalai gborin ejire lojumo
Koniye danu fawon eyan ton obese
Lalai gborin ejire lojumo
Allahu odo e latiwa
Dandan ni odo e lapada sio
Oku awon omo musulumi
Yah robbi dakun bawa sike won, ha,
Allahu odo e latiwa
Dandan ni odo e lapada sio
Oku awon omo musulumi
Yah robbi dakun bawa sike won
Awa laro pafewon olohun fewon juwalo
Awa laro pafewon olohun fewon juwalo
Dida oruko oloogbe mejeji, tiwon je obi fun (Alhaji akeem ay gold)
Allahu odo e latiwa
Dandan ni odo e lapada sio
Oku awon omo musulumi
Yah robbi dakun bawa sike won
Dida oruko alhaji akeem yinusa pelu awon ebi re
Allahu odo e latiwa
Dandan ni odo e lapada sio
Oku awon omo musulumi
Yah robbi dakun bawa sike won