Olorun Oba Imole (Hymn 205) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Olorun Oba Imole (Hymn 205) - Bisimanuel
...
Olorun Oba imole
Oba airy araiye e
Ologo didian Julo,
Waju eniti
Kekere ninu ese
Ki yio le sunmo O
To nfi ife pe elese
Lati r’ogo Re
Awon ti o fe lo npe
Awon to pe loyan a
Awon to yan lo se l’ogo
Laiye okunkun
Aiye nko ipe na
Nwon rin sinu
Okunkun
Lai fe ronupiwada
Labe iparun
Ire t’ale logba eden,
Ronupiwada a,
Wa si ibugbe imole,
Ibugbe ife,
Nibiti jesu njoba a,
Niwaju ite Baba,
Elese ronupiwada
Ma ko ipe na
Amin