- Genre:Gospel
- Year of Release:2017
Lyrics
Elo yi pada
Ara mi elo yi pada
Ara mi o eyi pada
Ara mi o eyi pada
Kuro
Kuro iwa erin
Iwa rede rede
Iwa pala pala
Ti ko je ka mo olorun mo
Ti ko je ka se rere
Elo yi pada
Ara mi elo yi pada
Eyi pada ara mi o
Ara mi o eyi pada
Kuro
Kuro iwa erin
Iwa rede rede
Iwa pala pala
Ti ko je ka mo olorun mo
Ti ko je ka se rere
Ile aye ile asan
Ile aye ile ishoro ni
Oun gbogbo o lo dede mo
Oun gbogbo o se dede
Nitori omo npa baba re
Baba nfi omo re showo
Iwa buburu lon gbin le
Awon eniyan ni ko ronu mo
Eniyan ko mo olorun mo
Eniyan buru o
Omo npa
Nitori omo npa baba re
Baba nfi omo re showo
Iwa buburu lon gbin le
Awon eniyan ni ko ronu mo
Eniyan ko mo olorun mo
Eniyan buru o
Elo yi pada
Ara mi elo yi pada
Mo wi to elo yi pada
Ara mi o eyi pada
Kuro
Kuro iwa erin
Iwa rede rede
Iwa pala pala
Ti ko je ka mo olorun mo
Ti ko je ka se rere
Toro lono sibi iye
Woro lono sibi iparun
Eni to ni ise nbo lojo kan
Lati shiro ise owo re
Ironu piwada ko si ni iboji fun elese leyin iku
Elo yi pada
Ara mi elo yi pada
Eyi pada mon ke tonton
Ara mi o eyi pada
Kuro
Kuro iwa erin
Iwa rede rede
Iwa pala pala
Ti ko je ka mo olorun mo
Ti ko je ka se rere
Oun koun tio demi lono iye meta lokan bami mu kuro
Oun koun tio demi lono iye meta lokan bami mu kuro
Dakun mono iye no
Rara koyi pada tori jesu lono iye ye
To lo to lo
Tori jesu lono iye no
To lo sile ogo (x2)
Oun alore un ke tantan
Rara koyi pada tori jesu lono iye ye
To lo to lo
Tori jesu lono iye no
To lo sile ogo
Dakun mono iye no
Rara koyi pada tori jesu lono iye ye
To lo to lo
Tori jesu lono iye no
To lo sile ogo (x3)
Jowo mono iye no
Rara koyi pada tori jesu lono iye ye
To lo to lo
Tori jesu lono iye no
To lo sile ogo
Toro lono sile ologo
Rara koyi pada tori jesu lono iye ye
To lo to lo
Tori jesu lono iye no
To lo sile ogo