Ife Aisetan (unfeigned love) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Ife Aisetan (unfeigned love) - Bose David
...
Iru ife wo leyi
Araye ko ye mi
Ofi omo bibi re kan soso
fun mi lati ku ni calvary
Ife lati gba mi la nigba to mio fe
Ife aisetan ,ife ododo
Chorus
Ife aisetan, ife ododo ni Jesu ni fun wa ooo
Ife aisetan, ife ododo ni Jesu ni fun wa (2ce)
Instrument :
Ife ti nu omije nu
Ife ti gba ni la
Ife ti nwo ni san
Ife to yitan Naomi pada
Ife to dariji ole, apa otun ni calvary
Chorus
Chorus
Ife aisetan, ife ododo ni Jesu ni fun wa ooo
Ife aisetan, ife ododo ni Jesu ni funwa (4ce)