Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2022

Lyrics

Olorun to lana lori agbami okun

Baba O ku ise

Eni t'afefe ati iji n gbo ti Ẹ

Baba O ku ise

Eni to tedo sinu agbara iyanu

Baba O ku ise

Asiri orun at'ohun gbogbo ton gbe inu ẹ

Baba O ku ise

Eni faja gbe Elijah lo si orun

Baba O ku ise

Eni fowo ina bora bi aso

Baba O ku ise

Eni ti iseti aso re kun tempili

Baba O ku ise

Agbagba merinlelogun wọn juba Re

Baba O ku ise

Eni to soro, ti aye wa riri

Baba O ku ise

Iwo loju imole to tan sori aye mi

Baba O ku ise

Agbara ton yii igbekun eda pada

Baba O ku ise

Agbara ton tun ayanmo eni se ni

Baba O ku ise

O mu awon onirora aya lara da

Baba O ku ise

O mu koriko dagba lori awon oke nla

Baba O ku ise


E ba mi kii daadaa

Baba O ku ise

Baba O ku ise

Baba O ku ise

Baba O ku ise

E kii daadaa

Baba O ku ise

Baba O ku ise

Baba O ku ise

Baba O ku ise


Abanise Adeyanju Oluporo ina Ibere ati opin

Olorun nla Kikida agbara

Ó ba Mose soro lojukoroju

Ei Agbara Israeli Ó seun gan ni

Itedo orun ohun aye


Ha Ariiritan Awaawatan Ayiniyintan O-gbenu-okun-yinbon

Ẹri olotito Abanimulemadani

Edidi aiye ti mo fehin ti

Eti to n gbo (Yes)

Gbogbo ede (Yes)

Aiku ni O, aiti ni O

Aisa ni O, Olorun awon akoni

Ase itura to fopin si inira mi

Kabiesi, owo to daso aponle fenikan o, to fa tenikan ya

O daso aponle f'Esteri, O fa ti Fasiti ya


Toto o toto ola Re Baba mi

Baba O ku ise

Oke nla arogun ma tidi o

Baba O ku ise

Olorun to dagba dagba ti ko ni itan

Baba O ku ise

Iwo ti O joko ninu olanla ogo Re

Baba O ku ise

Agbara to fi manna bo Israeli laginju

Baba O ku ise

Eni to gba won lowo Farao amunisin

Baba o ku ise

Asiri to pin okun si meji nijosi

Baba O ku ise

Asiri iwosan inu omi Bethesda

Baba O ku ise

Agbara to fi igi pe irin jade ninu omi

Baba O ku ise

Okuta to jolo to bi Goliati subu

Baba O ku ise

Iwo ti o ti wa saju ipile aye

Baba O ku ise

Eni ninu Eni ti agbara n gbe

Baba O ku ise


Olorun mi o

Baba O ku ise

Baba O ku ise

Baba O ku ise

Baba O ku ise


Baba O ku ise

Baba O ku ise

Baba O ku ise

Baba O ku ise

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status