Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2017

Lyrics

Korin si oluwa iwo okan mi

Sibi ayo korin mimo s’olu orun

Gbogbo eniyan e pe okiki oruko re

Ka fayo gbega

Korin si oluwa iwo okan mi

Sibi ayo korin mimo s’olu orun

Gbogbo eniyan e pe okiki oruko re

Ka fayo gbega


Oluwa seun anu re duro lai

Iyanu ni ise agbara olorun mi

Awamaridi awimayehun

Atofarati loun gbe inu orun

Kabiyesi olorun ogo ose

Gbigbe ga nio olorun ga ju awon oke lo


Korin si oluwa iwo okan mi

Sibi ayo korin mimo s’olu orun

Gbogbo eniyan e pe okiki oruko re

Ka fayo gbega


Eyin orun ema yo ire wole de

Eyin aye e gbe jesu ga o

Ese loba eyin eda aye

Eke kabiyesi fun oba ologo julo


Korin si oluwa iwo okan mi

Sibi ayo korin mimo s’olu orun

Gbogbo eniyan e pe okiki oruko re

Ka fayo gbega


Oba to mu afefe ati iji panumo

Oba to le sun nigba tiji aye le

Ofi okun kun okan ala re

Ile iso agbara ni oluwa wa


Korin si oluwa iwo okan mi

Sibi ayo korin mimo s’olu orun

Gbogbo eniyan e pe okiki oruko re

Ka fayo gbega


Orin mimo tawon ta ti rapada

Orin mimo tawon ta se logo

Orin ayo seni to ga julo

Orin ogo la o ko pade olorun wa


Korin si oluwa iwo okan mi

Sibi ayo korin mimo s’olu orun

Gbogbo eniyan e pe okiki oruko re

Ka fayo gbega


Biko ba se pe

Biko ko ba se pe oluwa

Ti oti wa ni tiwa

Orin kila wa yi ba ma ko loni

Nigbati awon ota dide o

Biko ba se pe

Biko ko ba se pe oluwa

Ti oti wa ni tiwa

Orin kila wa yi ba ma ko loni

Nigbati awon ota dide o


Won ba bori wa

Won ba ti gun wa mole

Bi pharaoh leyin omo isreali

Sugbon jesu ja fun wa

O gbe wa leke

A ju asegun lo


Biko ba se pe

Biko ko ba se pe oluwa

Ti oti wa ni tiwa

Orin kila wa yi ba ma ko loni

Nigbati awon ota dide o


Ere kilo wa ninu egbe mi

Nigbati mo ba lo si idake je

Oku ko le yin o logo o

Tori eyi ni mo sen shope


Hallelujah

Hallelujah si baba

Hallelujah somo re

So logo meta

Hallelujah si emi mimo o

Hallelujah so logo meta


Hallelujah

Hallelujah si baba

Si baba o

Hallelujah si omo re

So logo meta

Hallelujah si emi mimo

Hallelujah so logo meta


Oba iye

O shey

Oba mi

Olorun mi

Eri otito

Alagbara giga

Giga giga giga


Oba iye

O shey

Jesu mi o

O shey o baba


Oba iye

O shey

Eni wa o ko ri o

Eni ri o ko mo o

Mose lo ri akoyin si re

Oju re ran bi orun

Mono mono ton se oju orun

Yeri yeri yeri


Oba iye

O shey

Jesu mi o

O shey o baba


Fun wiwa to wa saye

Sun iku agbelebu

Fun emi mimo olutunu to ran si wa o

Fun ore ofe re to gbawa la

La se gbe o ga


Hallelujah

Hallelujah si baba

Hallelujah so omo re

Hallelujah si emi mimo

Hallelujah si ologo meta


Hallelujah si baba

Hallelujah so omo re

Hallelujah si emi mimo

Hallelujah si ologo meta


Ope lo ye eledumare oba mimo

Iyin lo ye jesu kristi oba ogo

Oba to fi ite re sile nitori elese

Tori ka ba le ri iye ayeraye

Tori ka ba le ni iye ayinipekun

Awa ri fun o eleru niyin

O seun o


O seun baba oba igbala

Tori satani ti mofo laye mi

Moni baba to le gbami

Moni baba to le gboro mi

Oun gbenu mi

Oun gbenu re

Alagbara loba ti mo gboju le


A alagbara loba ti mo gboju le

Alagbara loba ti mo gboju le

Talo dabi olorun ninu awon alagbara

Alagbara loba ti mo gboju le

Ogba heberu meta ninu ino eleru

Alagbara loba ti mo gboju le

O pa iji lenu mo o

O pin okun niya

Alagbara loba ti mo gboju le

O mu omi jordan gbe niwaju omo isreali

Alagbara loba ti mo gboju le

A alagbara loba ti mo gboju le

Alagbara loba ti mo gboju le


Moni baba to le gba mi

Moni baba to le gboro mi ro

Oun gbenu mi

Oun gbenu re

Alagbara loba ti mo gboju le


Ewi fi awon alayilaya wipe

Jesu mi nkoja

Jesu nkoja lo ni

Baba mimo koja lo

Loni loni

Loni loni

Baba wa yio wa ni itosi

Shi okan re paya lati gba

Tori jesu nkoja

Niyi yio koja

Nkoja niyi loni


Arakunrin jesu nduro

Lati dariji lofe

E se to oko gba nisinyi

Gbekele ore ofe re

Anu ati ife re showon

Ko jino si o loni

Wa shi ilekun okan re fun

Oti sunmo itosi re


A oun bo lati bukun o

Iwo fi irele teriba

Bo ara wo ninu ese

O se tan lati gba o

Iwo adeko igbala yi

Ti jesu fi ro o

A shilekun okan re fun

Oti sunmo itosi re


Jesu nkoja lo ni

Baba mimo koja lo

Loni loni

Loni loni

Baba wa yio wa ni itosi

Shi okan re paya lati gba

Tori jesu nkoja

Niyi yio koja

Nkoja niyi loni


Jesu mi nkoja lo

Nkoja niyi loni

Wo kori iye re gba

Nkoja niyi loni

Ranti dafedi lori igi

Nkoja niyi loni

Ojo yen ni igbala wole re

Nkoja niyi loni

Toripe ogba jesu loluwa

Nkoja niyi loni

Wa gba tire loni o

Nkoja niyi loni

Igbagbo ninu re lo fe o

Nkoja niyi loni

Ireti loruko re lo daraju o

Nkoja niyi loni

O de lati fun o ni iye

Nkoja niyi loni

Jesu mi nkoja lo

Jesu nkoja lo niyi

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status