Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2010

Lyrics

Ibi kan wa ti mofe lo

Ibi tawon angeli korin

Ilu mimo ilu elewa

Paradise orun

Talo fe lo o

Ibi kan wa ti mofe lo

Ibi tawon angeli korin

Ilu mimo ilu elewa

Paradise orun

Talo fe lo o


Ilu mimo paradise

Ibi ayo tawon seraph korin

Igba wo lemi yio ri ilu ogo re wo

Baba to mi sono

Baba to mi sono

Baba to mi sono ilu ogo


Ilu mimo

Ilu mimo paradise

Ni paradise ile ogo

Ibi ayo tawon seraph korin

Ibi tawon angeli sono o

Igba wo lemi yio ri ilu ogo re wo

Baba to mi sono

Baba to mi sono

Baba to mi sono ilu ogo


Paradise ilu ogo

Okan mi wa o lati sin

Igba wo niwon ri o ilu ayo

Ibi tie kun ose koni si mo


Ilu mimo

Ilu mimo paradise

Ni paradise ile ogo

Ibi ayo tawon seraph korin

Igba wo lemi yio ri ilu ogo re wo

Baba to mi sono

Baba to mi sono

Baba to mi sono ilu ogo


Awon apostli jiya lono ajo yi

Awon to ti koja lo won farad a iya ati irora

A so won ni okuta

A wo won nile

A gbe won sewon

Won nile lono yi ninu ishoro tori ati yege


Ilu mimo paradise

Paradise ile ogo

Ibi ayo tawon seraph korin

Igba wo lemi yio ri ilu ogo re wo

Baba to mi sono

Baba to mi sono

Baba to mi sono ilu ogo


Ono ilu ogo orike oluwa ni

Awon lowo mimo ti won si ni aya funfun

Awon ni yio bawon dele ayo


Ilu mimo

Ilu mimo paradise

Ibi ayo tawon seraph korin

Igba wo lemi yio ri ilu ogo re wo

Baba to mi sono

Baba to mi sono

Baba to mi sono ilu ogo


A so stephen lokuta tori iyin rere

Emi mimo ba le stephen oriran orun

A mu kori ogo to wa leyin iku olododo

Ori jesus kristi omo baba nite ogo


Ilu mimo paradise

Ni paradise ile ologo

Ibi ayo tawon seraph korin

Tawon angeli nko mimo mimo

Igba wo lemi yio ri ilu ogo re wo

Baba to mi sono

Baba to mi sono

Baba to mi sono ilu ogo


Ore mi je kalo o

Oya akoko ti to oya

Ore mi je kalo o

Oya akoko ti to oya

Ile mimo paradise

Oya akoko ti to oya

Ewa ogo re tuni lara

Oya akoko ti to oya

Ewa ogo re wunmi lopo lopo

Oya akoko ti to oya

Awa eniyan mimo la o wole

Oya akoko ti to oya

Nibi ta o ma ko mimo mimo

Oya akoko ti to oya

Mimo mimo

Mimo mimo

Oya akoko ti to oya

Alagbere koma ni wole rara

Oya akoko ti to oya

Ewa ogo wun mi lopolopo

Oya akoko ti to oya

Ah ore mi je ka lo

Oya akoko ti to oya

Ore mi je ka lo

Oya akoko ti to oya

Ore mi je ka lo

Oya akoko ti to oya

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status