Lati Ona Jinjin Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Lati Ona Jinjin - CCC Akoka Parish Choir
...
...............drum beat
..............
Lati ona jinjin
Eya aye gbogbo
Wo bi ojiji ti n fo lo
Gbo b‘awon eniyan
Ti n ke lohun rara
Ara e wa ran wa lowo
Chorus: ijoba orun nbo, eso itan ipa re
Aogbasa olorun s’oke
Aye yo kun fun imo ogo oluwa
Bi omi ti n bo okun nla
All: lati ona jinjin......