Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2022

Lyrics

O GBODO SE IYANU LAYE MI - EVANG. GBENGA OYOLOLA

...

iwo lole gbami lowo ogun, Olorun

ogun laye

iwo lole gbami lowo ogun

Ogun aye


nitori pe iwo ni Olorun

O nrin ninu agbara

o nsoro ninu agbara

o na eyan ninu agbara

o npe eniyan ninu agbara

o ngbe ni de ibi OGO oooh

ninu agbara, agbara to ju agbara lo

oro to ju oro lo

ase to ju ase lo

ohun to ju ohun lo oo

Oba to ju oba lo

O nro oba loye

O npe oba ranise

Iwo na ni (2x)

iwo na ni oo

Oluaye

Oluorun


(beats)


O gbodo se iyanu laye mi

toripe mo mò Ó l'Olorun ni

Iyanu ooh

Baba se iyanu laye mi

Olorun ooh

Baba se iyanu laye mi

Eledumare alagbara loje, mo mò yin daada

E le se jube lol

Baba se iyanu laye mi, koju ma ti mi oo


Iwo lole se oo Olorun mi

Iwo lo lana si ori okun pupa

Iwo ti okun ri ti osa

Jordani ri O, o pada seyin ooh

kilose o iwo okun ti o fi sa?

kilose o jordani ti o fi pada seyin oo?

wa riri iwo ile oo

gbogbo ogo to nbe ninu re po won jade, iwo ile maa gbo

fi f'awon to ni ogo oo jare


Olorun oo

isele ta sele ti mafi gbagbe oshi

isele ta sele ti mafi gbagbe iya

isele ta sele ti mafi pade olore mi, ti mafi gbagbe oshi

je ko sele ki osu yi to pari

(2x)


awon egbon josefu oo

won ri irawo josefu oo

won ta josefu soko eru

ko ma ba rogo lo oo

isele sele tori josefu

oba laala koba le rogo lo oo

ounje wa fun odun meje, iyan mu fun odun meje oo

Olorun eledumare se temi nire


Iwo lole gbami lowo ogun, gbami oo

Iwo lole gbami lowo ogun, gbami oo Oba rere

Baba gbami oo, edumare o jare

Baba

Iwo lole gbami lowo ogun, gbami oo Iwo lole gbami lowo ogun, gbami oo Oba rere

won ni mi o l'alawo oo

won ni mi o lonisegun oo

won ni mi o ni woli, mi o ni pastor

Olorun oo jare

O ba saanu mi

O ba ran mi lowo oo

Baba gbe mi debi ogo jare oo Olorun mi


Gbogbo ipe to ti sogo

mo fi suure fun ori mi

ki won wa gbe mi debi ogo, ki won wa gbe mi de Ile ileri

(2x)


gbogbo ipe to ti sogo oo

ipe Olorun Orimolade

ipe Olorun Oshofa

ipe Olorun Babalola

ewa gbemi debi ogo, ewa gbemi debi iserere oo Olorun mi


gbogbo ipe to ti sogo

mo fi suure fun ori mi

ki won wa gbe mi debi ogo, ki won wa gbe mi de Ile ileri

(2x)


Mama mi Esther Ajayi oo

ewa suure fun ori mi

Mama mi New Seraphim Soloye, Mama mi o ninu ire

Olorun ipe Baba Adeboye

ewa suure fun ori mi ooooo

lojo ti mo laala, ti mo ti Baba mi ti won gbadura fun mi

Ojo yen ni mo ti mowipe ala rere mi maa de

Iwo l'eledumare Olorun jare oo


Se iyanu re laye mi o Baba

Se iyanu re laye mi o Baba mimo

Se iyanu re karaye lema nroyin

ise re laye mi

(2x)


o se iyanu laye Jabesi oo

apoti Eric to pa USA oo

o wole Obediodomu, oso dolowo, oso doloro koto pe osu meta oo jare

Baba se iyanu re Kaye le ma royin, ise re laye mi


Se iyanu re laye mi o Baba

se iyanu re laye mi o Baba mimo

se iyanu re karaye lema nroyin

ise re laye mi


ipinmi, ipin rere ni mo mu waye

ipinmi, ipin rere ni mo yan

Ogun Ile lo Fe yi ipin mi

ogun ota lofe yi ipin mi pada

mi o si aye wa, ile ni mo si ya (2x)

opelope Jesu to gba ipin mi lowo wan, mo sogo


mo ti rire mubo ninu Jesu, eni oni Jesu, o mama se fun

mo ti rire mubo ninu Jesu, ayo loku mi ku mo sogo

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status