She said yes Lyrics
- Genre:Blues
- Year of Release:2022
Lyrics
She said yes - Yesaloonaka
...
...
Al yeseery
Ojo ojo kan ni moun lo soja ni
Mo ba ri ara birin kan ton bo leyin mi
O rewa gidi gan
Koda o ju emi lo
اخد لة حيفاه في خلقه
مجدرة اجزاه في وزنه
Mowa salamo si bo Shay to bo shay ye
Lo ba daun Pada wa aleikum salam
Mo ba so fun wi pe
Sha le joko soro
O ni ko soro pe ki ma so gboloun kan
Mo folorun be gan
Shugbon ko fe gba ni
Olowun kan ju baba oun reti oun
Olowun kan ju iya oun reti oun
Loba fimisile Larami ban gbo gan
الحب نار غادة حامية
Ni mo ba gba tele lati mu Aniyan she
Mo fe tele dale lati mo haduudu won
Lo ba sofun mi pe ki mashe dele awon
Baba mi buru gan dakun ma sha shesin
....
... ❤️❤️
Ife oni gba kin fi e sile ni
...
...
Ni moba sofun pe iwo arabirin
Mashe worry nipa baba re to buru
Akikanju ni mi egba won ko le bami(yeseer)
Ida n be lowo mi ma fi shora mii
...
Lo ba tun wa sope ona ile wa jin gan
Petesi ile wa o ga gan doke nii
O ni le gun se iwo arakurin
...
Ni moba so wipe oke ki sha ishoro
Latigun funmi nitori iwo ododo
Eleyinju ege
Even ko je sama nii
Dakun ma sha honour wiwa si ile eyin
Ife o ni gba kin fi e sile niii
...
O tun wa so wipe odo n be ni ile awon
Ni itori to ba wa
Odo ma gbe e lo
...
Mowa sofun wipe wedo wedo Lemi
Mio ni ishoro nipa odo ile eyin
...
O to so pe ekun n be
To rokirika
Mionishoro nipa odo ile eyin
...
Otun wa sope eyan meje Lon sho oun
...
Ti won ba mu e ilukilu ni won oo na e
...mowa so fun wipe sho ri e mi na