Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2022

Lyrics

GBANI ft. Daddy Verse & Oshara - LC Beatz

...

Intro

LC Beatz

Mo ti farabalẹ, lo ni groovy groovy

Chorus:

B'o ti lẹ wu k'ori eee yeee

Ore ọfẹ ṣi n gba ni

B'o ti lẹ wu k'ori eee yeee

Ore ọfẹ ṣi n gba ni

Chai! Sa're w'ọkọ igbala

Baba ṣi tun n gba ni,

Jesu Kristi n gba ni

Gbani gbani t'on gba ni

Chai! Sare w'ọkọ igbala

Baba ṣi tun n gba ni,

Jesu Kristi n gba ni

Gbani gbani t'on gba ni

Verse

Daddy O!

Eeeh... Aaah Eleven ti wa ni'ta ọrẹ

Awa la p'eero s'ọkọ

Ẹru'ku farabalẹ, ko r'igbala ọfẹ

Wọn 'ma ni beere kọbọ

Ẹyin ti National, ẹyin ti Road

Awọn temi lati Lẹkki d'Ajah

Jesu lo n gbani la, you know the code

Sabo Yaba gan, wọn sare wa gba

T'o ba ti le danfo iye gba

Ọmọ ọka n fo, ide ja

Ọmọ the blessing, you go pack ooo

Inu bagco, o le gba

Ẹni mọ Jesu, b'oṣo bá n ké, b'àjẹ ba n fo, o lè pàá

Jesu go dey there o, b'ojo ba'nrọ, b'ina ba n jo, ko le sa

E dey save anybody

Awọn to ṣe'mu rogodo, a bọ n ṣ'ori kẹndi

A'bawọn fresh, awọn ti wọn wọ Balenciaga sori Fendi

A'bawọn razz, awọn t'ọn ro pe o ti tan fun, pe life-u ti bend-i

Wo! Wa gbọ fact, ko saye to kan ti Jesu Kristi o le mend

Bruh...

Chorus:

B'o ti lẹ wu k'ori eee yeee

Ore ọfẹ ṣi n gba ni

B'o ti lẹ wu k'ori eee yeee

Ore ọfẹ ṣi n gba ni

Chai! Sa're w'ọkọ igbala

Baba ṣi tun n gba ni,

Jesu Kristi n gba ni

Gbani gbani t'on gba ni

Chai! Sare w'ọkọ igbala

Baba ṣi tun n gba ni,

Jesu Kristi n gba ni

Gbani gbani t'on gba ni

Verse

???

Fẹjẹ Fẹjẹ (Afẹjẹ w'ẹṣẹ)

Ẹrujẹjẹ (???)

To ba ti ni bo ṣe ma jẹẹ ni yẹn

Gẹgẹ bẹ lo ṣe jẹ gẹgẹ

Ko si bo'e jẹ

Ya gbo-Yaá jù (Ya gbo-Yaá jù, Erin lakatabu)

Milẹ milẹ ju ṣakabula

Boom...boom...boom...boom...Shakala...boom

Ijọ to mo ti tẹle Jesu

O gba mi l'ori mu, a fi bi pencil

Lo ti n fi mi y'àwòrán ayọ

Y'àwòrán ire, sọ mi d'ina, sọ mi d'iyọ

Iṣẹ ti yatọ si ti tẹlẹ, of course,

Okay, ki lo fẹ bami sọ, ki la n discuss?

Aisan...(nonsense)

oṣi..( nonsense)

ẹṣẹ...(nonsense)

eṣu...(nonsense)

Aaaahhh, ibẹru ko si,

Ifoya ko si

Ìdáríjì wa, a f'ẹni ba gb'odo mi l'oku

Bros, ìjìyà ko si

Anybody ló lè change

Ama f'adura ja gbogbo chain (chain...chain...chain)

All I need is 1 Halleluyah, go and bring your 10billion eriwo-ya

Ba'ṣe wọkọ yẹn la yatọ (bẹẹni)

aye oṣi yẹn la parọ

Iwọ na le wa...ko gbá rù kù tìí

fún to ba jẹbi apà'yàn

A bo ti fẹ'mí ẹ gbààrọ? (woooohh)

A bo f'ẹrìn ẹ ta'yàn? (aaaahhh)

Gb'ogun jẹdi à f'atọ

?????

Wa n bi, Brotherly

Ọkọ ti ṣíná wọlé gan gan

Iwọ ṣa ti wọlé, Jesu Kristi ṣa ni busstop

O ni normally, ẹni wọkọ gan lo ti gbọn-gbọn

Ọfẹ dẹ tun ni, ìdùnnú mi ni pè ko mọ

Baby, sáré wa wọ bus yẹn

Oun to ní lò ma plus ẹ ẹ

O wa ni need lati la tan fún boss ẹ ẹ

Abi ko darọ ni church ẹ ẹ

Ẹrù ayé yìí wúwo jù

Ọrẹ, ma ṣe àdágbé...àdáfà

Ọlọrun Oba ti mọ ẹ jìnà

ki wọn to ṣeré Mummy and Dadda

Chorus:

B'o ti lẹ wu k'ori eee yeee

Ore ọfẹ ṣi n gba ni

B'o ti lẹ wu k'ori eee yeee

Ore ọfẹ ṣi n gba ni

Chai! Sa're w'ọkọ igbala

Baba ṣi tun n gba ni,

Jesu Kristi n gba ni

Gbani gbani t'on gba ni

Chai! Sare w'ọkọ igbala

Baba ṣi tun n gba ni,

Jesu Kristi n gba ni

Gbani gbani t'on gba ni

Chai! Sare w'ọkọ igbala

Baba ṣi tun n gba ni,

Jesu Kristi n gba ni

Gbani gbani t'on gba ni

Chai! Sare w'ọkọ igbala

Baba ṣi tun n gba ni,

Jesu Kristi n gba ni

Gbani gbani t'on gba ni

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status