SOMETIMES Lyrics
- Genre:Afro Soul
- Year of Release:2022
Lyrics
Oyomesi
Inu mi loro ngbe
lekokan moma nderu bara mi
Ara Ile, Ero Oja
Odele tan Elanu gbaga
Aja te ran ko lo silekkun
Kokoro ti beyin aja je
ilu le koko bi oju eja
Ao le gberi ara wa je o
Ala fe koja
Elo deyin ola, Ola detan
Kaka ka koja etun dawa koja
Awon oniroyin
won ti royin
Awon to motivate
won motivate mi lowo
Kurukuru de boju ojo
koseni to rira won mu lowo
Obuko nbomu fasin
Ore Ofe lari jurawa lo
Osun momi o
O jina simi
A sebi eni de
Igbami a Sebi eni wo
Osun momi o
O jina simi
A sebi eni de
Igbami a Sebi eni wo
Ogun Ilu ta nforija
Oju tile
Awon kan fara sinu ku
Awon kan ku sori ere
Ere asa pajude
Ko jale sun pajude
Bope boya baba darugbo
Gbogbo e a pajude
Awon oniroyin
won ti royin
Awon to motivate
won motivate mi lowo
Kurukuru de boju ojo
koseni to rira won mu lowo
Obuko nbomu fasin
Ore Ofe lari jurawa lo
Osun momi o
O jina simi
A sebi eni de
Igbami a Sebi eni wo
Osun momi o
O jina simi
A sebi eni de
Igbami a Sebi eni wo
Osun momi o
O jina simi
A sebi eni de
Igbami a Sebi eni wo
Osun momi o
O jina simi
A sebi eni de
Igbami a Sebi eni wo