Wakati Adura Didun Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Wakati Adura Didun - Sunday Babalola
...
Wakati adura didun!
t'o gbe mi lo kuro l'aye,
lo 'waju ite baba mi,
ki nso gbogbo edun mi fun;
nigba 'banuje at'aro
adua l'abo fun Okan mi;
emi SI bo lowo esu
'gbati mo ba gb'adua didun
Wakati adura didun
iye re y'o gbe ebe mi
lo sod'eni t'o se'leri
lati bukun Okan adura
b'o to ko mi ki nw'oju re,
ki ngbekele,ki nsi gba gbo;
un o ko gbogb'aniyan mi Le
ni akoko adura didun
Wakati adura didun,
je ki nma r'itunu re gba
Titi un o fi d'oke pisga
ti un o r'ile mi l'okere;
un o bo ago ara sile,
un o gba ere ainipekun
un o korin bi mo ti nfo lo!
o digbose adua didun.