Loading...

Download
  • Genre:Afrobeat
  • Year of Release:2022

This song is not currently available in your region.

Try the alternative versions below.

Lyrics

Interlude

Mashaallah


Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o

Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla

Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o

Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla


Tor'odi o loun tole fi toro, sungbon o lokan tole fi beere

O sha nd'odi loun lori oore, kod'igba tinba so soke kaye o gbo o

Koto dami loun oba nla ilahi


Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o

Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla

Yah robbi koma s'oba meji ti momo, l'oba tiwon npe l'olohun


Toba j'ese ti emi tinse, t'iyen fema dina ati gb'ore

Emi nf'akoko yi toro, aforijin lodo re o allah


Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o

Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla


Bee, mo l'awon nkan l'afojusun repete, nkan to wumi lokan pe kin ni

O wumi kin nile pupo timo ko o, pelu ile ise topo repete


Kin mari bukata gbo l'agbo dale o, kemi ma f'ewu ogbo agba t'ore

Eyi timo ranti bere ninu oore, eyi ti nranti bere ninu oore o

Maf'ikankan, dunmi nibe oba nla


Mo kepe e olohun mi, mo kepe e olohun mi,

Olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro


Mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro, naam


Ogun k'eda le koma leba, k'eda fa koma to'rawon

Iyen o wumi wa rami kale, maje nri'soro, olohun oba


Mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro

Allah, je k'enu mi t'oro ninu ebi wa,

Ma fami seyin ninu egbe kin tayo


Agbega lemi nfe, wa famisoke, oba alaranse, olohun oba

Mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro


Emi o sope owo o je nkan, miio de gbe'yi fun'le aye j'orun lo

Sungbon owo l'ale fise pupo n'nu ise ore toni kama se , mofe ma t'ore


Mo kepe e olohun mi, olohun jowo wa rami kale, majen r'isoro

Mashaallah, oluwa mi, oriyomi lemi nje, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo


Gbogbo ireti oore, je o tomi lowo ooo oti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo ha

Mote f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo


Gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo

A leni ma deyin ma deyin ota ile ton o fe ka r'ibi mi mo


Kos'iru áàlò t'ale se, kotun kin tewon lorun, bi k'ama se wa laye mo, lori loju ota wa

Mio ni ku f'ota yo lailai, ma gbe'le aye seun rere o


Moti f'oro ota gbogbo, fi l'oluwa lowo won gbe

Moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo


Gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo

Seri ibanuje ota nipe, won nrimi pe mo cute


Mio toro óbè tun gb'abo, losile awon eyan won

Kobe kiwon le so pe ebi pami de ile odo won


Atije atimu mi, mafi l'otami lowo, awon oro mi gbogbo, lowo oluwa lo ngbe

Allahumma ina, aj-aluka fii, nuh-rihim

Wa naudzu bika min, shururihim


Allahuma akfinihim, bima shi-ita, allahuma anta a-duhdi

Wa anta nasriy, bika ajulu wa bika, asuulu


Wa bika uqotil, hasbuna Laha, wa ni-imal wakeel

Moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo


Gbogbo ireti oore, e o tomi lowo o, moti f'oro mi gbogbo, fi l'oluwa lowo

Ok, eti e gbo, wona enemy mi da? won ti wo'gbo, won ti ra m'aye


Awon abinu eni da now? won ti wo'gbo, won ti ra m'aye

Awon amoni seni da? Won ti wogbo, won ti ramaye


Awon ota ologo da? Won ti wo'gbo, won ti ra m'aye

Awon ápání máyo'dà? Won ti wo'gbo, won ti ra m'aye


Tojepe loru na ma nfase ja? Won ti wo'gbo, won ti ra m'aye

Ise ti ati nsebo lati ipile wa, kole da ti ati nbabo lati ibere wa o


Eyi toku tota ndina ma salai shio, sebaje mafe gbayi nidi ibaje o

Da'na súnwon konma file r'aye t'awa mo, nitoripe


B'olohun se nsore e fun eru (Ota ngbogun ati tuka, yes

Ani b'olohun se nsore e fun eru, ota ngbogun ati tuka


Awa gbeke lolohun, ota ngbogun ati tuka

B'ase gbeke lolohun, ota ngbogun ati tuka


Eyin e ma wo'ran, e file o, ise lo gba o, fe s'eru ku niyen

Oya, so p'otami yeye aye e, yeyee, yeye aye e


Bimose nrije rimu kole ye e, ko lee, kole ye

Bimose nri t'owo se kole ye e ko lee, kole ye


Bimose ntoju ayemi, kole ye ko lee, kole ye

Gbogbo lilo bibo mi kole ye e, ko lee, kole ye


B'awon aye se nfemi kole ye e, ko lee, kole ye

Amóni séni ota ile, ko lee, kole ye


Olohun

Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, mafi'koro simo, mafi'koro simo

Adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan


Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan

Opo oore eda laye o,lonyi s'ibanuje

olohun ilahi, ma mase t'awa be


Towo batie wa wa, t'alafia o basi

Kini igbadun owo, se ka l'ore èdé ni

Ore ti o po dale oo, ore ti o po dale, olohun lemi fe


Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan

Won ni b'eye ègà kole o, yio f'enu re tu tan


Sebi funra ólókùnrùn, lo nfenu re pe iku, oore ti mo nfe o, pe kose ilahi

Toba ma dinira, dakun ba ns'atunse, toba semi bimo se fe o, ope mi o nitan


Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan

MashaAllah, moti nj'eni aponle o, maje npada wa te


Aye npemi s'ariya, t'owo pelu ebun nla, won nsemi l'anu, won a tun s'adua funmi

Mo l'olohun ma lase, loba sina anu, laba tun se'dera o, k'opeyemi le tele


Mafi'koro simo o, mafi'koro simo, adua mi ti ngba, dakun ba nsalekun, toba semi bimose fe o, ope mi onitan

Oriyomi, mo dupe f'awon fans, ton nf'owo ra data


Adupe f'awon fans, ton nf'owo subscribe

Adupe f'awon fans, ton, nfojojumo lo skit


Ope to seyin fans, te nf'owo ra cd, bee

Pelawon fans kan, ton npewa s'ode ere ton nawo, akanni, adua mi nipe o, k'olohun tunma se'bukun


Oba o ni dawo ola duro

Gbogbo be senri temi ro o, lolohun a ma ro'jo ike

Oba oni dawo ola duro


Gbagbo bese nfimi s'okan l'olohun a ma se'dunnu

Oba oni dawo ola duro

Hajji ibraheem dende, alase ibd ajao


Oba oni dawo ola duro

Sheu ganiyu akewushola olohun ni idahun s'adua


Oba oni dawo ola duro

Hajji razak arolat mi, ágbã owo tonpe l'àgbà awo

Oba oni dawo ola duro


Akeweje iseyin, baba adini of nigeria, oba oni dawo ola duro

Alhaji lukman mi o, omo shittu zangallo zanga


Oba oni dawo ola duro

Alhaji ridwaanullahi, olamilekan dansokoto

Oba oni dawo ola duro


Akanmu agba omo bakare o, hajji rashidi agunwa

Oba oni dawo ola duro

Hajji saheed omo olayode o, akan'o oko ejire, oba oni dawo ola duro


Omo agbaje shereefdeen mi, ola salam ni okan ni, oba oni dawo ola duro

Babatundé ibon, abdul majeed l'olufimo, oba oni dawo ola duro


Mio je gbagbe awon manager mi, tajo nse tofi ndun to ndan, oba oni dawo ola duro

Ayesoro innocent ahmed, baba aliyah oko nafisat


Oba oni dawo ola duro

Adisa ade emir mi, ayomide ismaheel, oba oni dawo ola duro

Owolabi lukman mi, baba fausat anisere, oba oni dawo ola duro


Irawo toyeeb olamilekan, steady boy akorin ni

Oba oni dawo ola duro

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status