MAJOBA LO Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Hallelujah si o Baba
Hossana fun o Jesu
Ma gesin lo o
Ninu olanla re
Ninu aiye mi
Majoba lo
(Hee)
Hallelujah (Hallelujah)
Si o (Si o) Baba (Baba)
(Hossana) Hossana (Fun o Jesu) Fun o Jesu
(Ma gesin lo)
Ma gesin lo oo
(Ninu olanla re oo)
Ninu olanla re o
(Ninu aye mi majoba lo)
Ninu aiye mi majoba lo
(Jesu Kristi ma joba lo)
(Ijoba re laye mi dara)
(Kos'eni to le se oun ti wo se Laye mi Jesu majoba lo)
Hallelujah si o Baba
Hossana fun o Jesu
Ma gesin lo ninu olanla re
Ninu aye mi
Ma joba lo
Hallelujah si o Baba
Hossana fun o Jesu
Ma g'esin lo ninu olanla re
Ninu aye mi
Ma joba lo
(Gba gbo iyin Oluwa)
(Gba gbogbo ogo at'ola)
(Iwo nikan lope mi ye)
(Jesu Kristi ma se dawo ise duro)
(Halleluyah si o Baba) Hallelujah si o baba
(Hossana fun o Jesu)
Hossana fun o Jesu
(Ma g'esin lo o ninu olanla re)
Ma g'esin lo o ninu olanla re (Ninu aye mi ma joba lo)
Ninu aye mi ma joba lo
Halluluyah
(Hallelujah) si o baba
(Si o baami)
Hossana (Hossana) fun o Jesu (Fun o Jesu)
Magesin lo
(Magesin lo o ninu aye mi oo ma joba lo)
Ninu olanla re
(Ninu aye mi majoba lo)
Ninu aye mi majoba lo
(Hallelujah heee)
(Hallelujah heee)
(Jesu Oluwa mi o ojoba o titi lai)
Hallelujah heee
Hallelujah heee
Jesu Oluwa mi o ojoba o titi lai
(Hallelujah heee)
(Hallelujah heee)
(Jesu Oluwa mi o ojoba o titi lai)
Hallelujah heee (Ojoba laye mi)
Hallelujah heee (Ojoba ni le mi)
Jesu Oluwa mi o
O joba o titi lai
Halluluyah si o Baba
Hossana fun o Jesu
Ma gesin lo o
Ninu Olanla re o
Ninu aye mi ma joba lo