Loading...

Download
  • Genre:Gospel
  • Year of Release:2022

Lyrics

Ijinle Ninu Ijinle - Niyi Fadipe

...

Mo gbe oga o, metalokan ijinle, kabiyesi re o, alaanu mi ijinle, Tori ogbon re o ijinle ni, agbara re o ijinle ni, oruko re o ijinle, o koja oye eniyan ijinle ni, awamaridi ni ijinle ni,

Ijinle ninu ijinle mo gbe oga o.

Chrs:-

Ijinle ninu ijinle, o seun /4x

Ana mi soro o seun o

Oni mi soro o seun o

Ola mi a soro o seun

Ijinle ninu ijinle o seun o

Intro

Ko soba bi re o

Metalokan iwo ni ijinle

O mowo Jade lenu eja o,

Ko yeniyan o, toripe wo ni ijinle

Agbara re o (Baba) ijinle ni,

Ogbon re o ijinle ni,

O koja oye eniyan ijinle ni,

Won wa wa won ori o ijinle ni

Ko la fi we o rara rara ijinle ni

Ijinle ninu ijinle mo mo gbe o ga o


Chrs:-

Olorun mi bojuwomi....

E ba mi gbe ga o

Alagbawi ni ijinle

E fogo fun oruko Baba mi

Toripe ohun gangan gangan ni'jinle

Awon orun soro ogo re,

Ofurufu fi ise owo re han

Aye mi naa soro osoro lowolowo

O n soro o, o n soro ogo re,

Eh

Ana mi soro o seun o

Oni mi soro o seun o

Ola mi a soro o seun


Chrs:-


Bridge:- E seun o, e seun o, e seun o o o

Ijinle ijinle ijinle ijinle ijinle eeee

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status