Lo'Ja Fún Mi
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Lo'Ja Fún Mi - Lanre Teriba (Atorise)
...
Ẹ̀mí mímọ́ lọ jà fún mi níbi ìyànjẹ.
Ibi tí wọn kò ti gbọ́ tẹnu mi
Tí wọ́n f'èké dá mi lẹ́jọ́
Ẹ̀mí mímọ́ lọ jà fún mi níbẹ̀.
Ayé tá Jésù Kristi ní pọ́ọ́kú
Àwọn ẹ̀gbọ́n ta Jósẹ́fù nítorí ògo
Ohun tuntun kan ò si lábẹ́ ọrùn
Ìbàjẹ́ ènìyàn kò dá'ṣẹ́ Olúwa dúró
Ògo ayé Jósẹ́fù di múmúṣẹ
Àwọn tí ó le lọ ni wọ́n tún padà ń wa kiri.
see lyrics >>Similar Songs
More from Lanre Teriba (Atorise)
Listen to Lanre Teriba (Atorise) Lo'Ja Fún Mi MP3 song. Lo'Ja Fún Mi song from album Lo'Ja Fún Mi is released in 2024. The duration of song is 00:01:20. The song is sung by Lanre Teriba (Atorise).
Related Tags: Lo'Ja Fún Mi, Lo'Ja Fún Mi song, Lo'Ja Fún Mi MP3 song, Lo'Ja Fún Mi MP3, download Lo'Ja Fún Mi song, Lo'Ja Fún Mi song, Lo'Ja Fún Mi Lo'Ja Fún Mi song, Lo'Ja Fún Mi song by Lanre Teriba (Atorise), Lo'Ja Fún Mi song download, download Lo'Ja Fún Mi MP3 song
Comments (3)
New Comments(3)
janetmotunrayo706@gmail.com
cephasola
Sir if you read this comment pls upload Unstoppable God on this platform
cephasola
My favorite
sir I love this one please sir can you do me a song sir of emimimo ni oba wa please sir