Eyin Oluwa Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Eja ka fope fun o e iwa olorun yin topo
Eru ipa re po o e be lanu re duro lailai (eyin oluwa o)
Eyin oluwa alleluyia egbe ga o o alleluyia
Eyin oluwa alleluyia oun lo ga ju o o alleluyia
Iyin oun to fogbon da orun iyin oun to lewa ninu ogo
Iyin oun ti cherubim & seraphim ko si o
Oun re ku awon omi okun

Nitori majemu ati ipinle ese
Nitori ododo re ti ko sa kiri
Nitori irele ati ife re siwa
Nitori agbara re to po pupo

Iyin oju ogo re ti kin pada
Iyin owo ina re to kun fun abo
Oun gbogbo to da o da won dara dara
Iyin oun tangelo juba ni gbagbogbo

Yin tinu tinu re yin gbogbo tokan tara
Yin bawon torun wo o oun lo ni ife wa julo