Enu Eniyan Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Kile ma dahoro la mi tantan
Koro ma dariwo la un ki bosi
Komo eleran ma pada wa jegun
Enitolaso ko ma pada wo akisa
Eniyan ro eniyan ro ko ma ba se lorun oba
Mo leyan ro eniyan kese e ma ba jare re
Kile ma dahoro la mi tantan
Koro ma dariwo la un ki bosi
Komo eleran ma pada wa jegun
Enitolaso ko ma pada wo akisa
Eniyan ro eniyan ro ko ma ba se lorun oba
Mo leyan ro eniyan kese e ma ba jare re
Ero to mo pe ile aiye yi awa naja e sumo bi
Ki gbogbo eni to sole aiye dawa yi lo ko ya ma gbo
Eni to ra unko ipa nu loja to dun se ko ni lo sile mo ni
Won dabi eni to ti gbagbe orun abe o mope ile labo simi oko
Ema tori aiye ke gbagbe orun moun ke tantan
Liyo ti dun niyan to be eniyan padanu ijoba orun
Komo eleran mi a jaso so wa da
Ese loro iku lere e orun apadi lon gbeni re
Kile ma dahoro la mi tantan
Koro ma dariwo la un ki bosi
Komo eleran ma pada wa jegun
Enitolaso ko ma pada wo akisa
Eniyan ro eniyan ro ko ma ba se lorun oba
Mo leyan ro eniyan kese e ma ba jare re
Loto alanu lolorun a ma dariji ni
Sugbon gbogbo elese ni o mo pe ese kin un se oun re
Ole ipanle agbere ote won ko ni lo sinu ina
Alatenu je oni gbagbe e ma so wiwa jesu di lasan
Agbero kin un ba oko rin jesu je ba o joba
Ki lere oni gbagbo to kede jesu to forum a padi se ile
Komo alaso ko ma wo akisa ese koma jare mi
Ebe mmo be ada ni waiye sanu fun mi
Kile ma dahoro la mi tantan
Koro ma dariwo la un ki bosi
Komo eleran ma pada wa jegun
Enitolaso ko ma pada wo akisa
Eniyan ro eniyan ro ko ma ba se lorun oba
Mo leyan ro eniyan kese e ma ba jare re
Gbe agbelebu tele jesu ogun aiye le koko
Gbe agbelebu tele jesu roju ko gbe sumo oluwa
Ajaga re rorun eru re si fuye gbe gbe gbe o