- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
Lyrics
Ayeraye ni o olorun mi o
Mo'gbe o ga oba gbogbo aye
Ayeraye ni o olorun mi o
Mo'gbe oba gbogbo aye
Bokunkun se le to kurukuru boju ojo, Aye ope yo feemi emaa maa se
Ayeraye ni o olorun mi o
Mo'gbe o ga oba gbogbo aye
Iwo naa ni oba lori aye gbogbo, obadarirurin oba gbogbo eniyan pata, obaye iwolobarunko iwo lolagbara lori ongbogbo toda kabiosi oo osuba re oo, olagbara lori awon otami gbogbo, okomiyo ninu ikekun peyepeye ife re laye mi o'tobi jonrinjonrin, kabiosi olorun toni gbogbo igba mi lowo osuba re ree olorun mi o.
Ayeraye ni o olorun mi o
Mo'gbe ga oba gbogbo aye
see lyrics >>Similar Songs
More from Olatomiwa Timileyin
Listen to Olatomiwa Timileyin Ayeraye MP3 song. Ayeraye song from album Ayeraye is released in 2023. The duration of song is 00:02:34. The song is sung by Olatomiwa Timileyin.
Related Tags: Ayeraye, Ayeraye song, Ayeraye MP3 song, Ayeraye MP3, download Ayeraye song, Ayeraye song, Ayeraye Ayeraye song, Ayeraye song by Olatomiwa Timileyin, Ayeraye song download, download Ayeraye MP3 song
Comments (1)
New Comments(1)
hollapress075m4
it's very fine job