Loading...

Download
  • Genre:Afrobeats
  • Year of Release:2015

Lyrics

Ògo ìyìn ọlá

Lóye Ọlọ́run

Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ògo Ìyìn ọlá

Lóye Ọlọ́run

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún


Ọba tó f'na hàn wá

Ọba tó lẹ́ mi wá

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun


Ọba tó f'na hàn wá

Ọba tó lẹ́ mi wá o

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún


Níbi tó lẹ́ wá julo Ní Ìwọ gbé

Lórí obiiri ayé níwọ̀ wá o

Imọ́lẹ́ láṣọ re

Ọlá lọ fi sa so bora


Níbi tó lẹ́ wá julo ni ìwọ gbé

Lórí obiiri ayé ni'wo wá o

Imọ́lẹ́ láṣọ rẹ

O ó Ọlá lọ fi ṣá sọ bora


Mo padà wá bí orísun ìfẹ́ àkókò

Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o

Ọba tó lẹ̀ mi mi

Ọba tó ní gbà mi


Mo padà wá bí orísun ìfẹ́ akoko

Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o

Ọba tó lẹ́ mi mi

Ọba tó ní gbà mi


Ahhhhh Ahhhhh

Ìwọ lọ lè mi ò

Ìwọ lo nígbà mi


Ìṣẹ̀lẹ̀ inú ìṣẹ̀dá ṣá'fihàn àgbàrá rẹ

Àwọn ohùn tàri ṣáá fihan ìṣe rẹ o

Pẹ̀lú ifilelẹ̀ tí ó lè Páráda láì láì

Àrà ọwọ rẹ ni gbogbo wọ́n


Ṣe bí èyí tàri là ń wi

Àwọn ohùn tá a ò lè rí má bùsan yeye

Àìmọye làwọn tá kò mo l' àrà

Ẹ̀dá ó lè ṣá kàwé wọn


Ibí tó lẹ́ wá julo ni ìwọ gbé

órí obiiri ayé ni'wo wá o

Imọ́lẹ́ láṣọ rẹ

O ó Ọlá lọ fi ṣá sọ bora


Mo padà wá bí orísun ìfẹ́ àkókò

Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi o

Ọba tó lẹ̀ mi mi

Ọba tó ní gbà mi


Mo padà wá bí orísun ìfẹ́ akoko

Mo ṣe tẹ fún ọ lógún ọkàn mi ò eh

Ọba tó lẹ́ mi mi

Ọba tó ní gbà mi


Ògo ìyìn ọlá

Lóye Ọlọ́run

Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún


Ògo Ìyìn ọlá

Lóye Ọlọ́run

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún


Ọba tó fún ní lé mi ọba tó lé mi ẹni tó lé mi gàn gàn

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún


Ogo rẹ pọ púpò ṣe bí èyí tàle fara gbà mú là ń jẹ fani ẹ

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun


Àìmọye àwọn èyí tá'kólé mọ̀ bíi kò ṣé bí a gbà sunmọ ibùgbé rẹ

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún


Ìyanu rẹ kọjá a fẹnu sọ ìwọ̀n bá ti ọgbọ́n orí lè gbé là ń ṣá pé júwe fún

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún


Olúwa àwọn ọmọ ogún kọjá àpèjúwe kò ṣe ní tó lè mọ ṣe rẹ

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún


Eni bẹ lórí ìtẹ́ á sì wà síbè sì bí ó ti wà láì láì ni yẹn ìyípadà kàn ó sì

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun


Gbogbo ògo gbogbo ọlá gbogbo ìjọba tìrẹ ṣá ní

Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún

Similar Songs

+

      -   or   -

      -   or   -

      NG +234

          Please Select A Playlist

          Add New Playlist

          Share on

          Embed: Love & Light EP

          Custom Size :

          • Default
          • Desktop(300*600)
          • Mobile(300*250)

          Type :

          • HTML/HTML5 (WordPress Supported)
          Get Boomplay Premium
          for
          Payment Method
          Pay With
            Review and pay
            Order Date
            Payment Method
            Due Today
            Flutterwave
              Subscription Successful

              Congratulations! You have successfully activated Boomplay 1 Month Premium.

              Now you have access to all the features of Boomplay App.
              Payment Failed

              Please check your balance and then try again.

              You'll lose your subscription if we don't have a working payment method for your account, so please check your payment details.
              Need help? Contact Boomplay Subscription Support.
              Payment Processing...
              10 s

              Payment is being processed by . Please wait while the order is being comfirmed.

              Payment Processing
              Your order is processing, and it may take up to a few days for the service provider to handle your payment. Please kindly stay tuned and check your order status in ‘User Center’.
              About Order Status