Asiko Lyrics
- Genre:Afrobeat
- Year of Release:2022
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
T reign on the mix
Asiko temi o f'ayo gba ire ayemi
Lasiko toto ati igba toye
Bimose nsin'lohun bo lojo ayemi o
Bo t'asiko to ye kin jere
K'emi irewesi maje ngbere itiju
Asiko temi o f'ayo gba ire ayemi
Lasiko toto ati igba toye
Bimose nsin'lohun bo lojo ayemi o
Bo t'asiko to ye kin jere
K'emi irewesi maje ngbere itiju
Mashallah
Olohun oba todawa o daju rara o
Tori poun sha loseto fun kowa wa
O m'asiko lati daun adua wa
Oba to kemi sha ni yio pada tun wa ke'wo o
Naam
Kiiba t'enikan je koto pada se felomiran
Gbogbo èrongba wa adi mimuse
Kama so igbagbo aye wa nu ka reti oore
Asiko temi o f'ayo gba ire ayemi
Lasiko toto ati igba toye
Bimose nsin'lohun bo lojo ayemi o
Bo t'asiko to ye kin jere
K'emi irewesi maje ngbere itiju
Bee
E kilo f'omo adama toba nkanju
Lojojumo lon nreniyan kan da lebi o bi Bio reni da lebi a d'olohun lebi
Abi k'otun pada wa ma dara e gan lebi o
Sewa reni tonsebe afi koyi pada o,yes
Kiise gbogbo wa nio da lohun tan lowo kan
Lasiko atigba tio fisi oun sha loye
Adua koma lo peju ni ka mugbo
Pe kale tete ri'gba wa lo k'ojo to malo
Asiko temi o f'ayo gba ire ayemi
Lasiko toto ati igba toye
Bimose nsin'lohun bo lojo ayemi o
Bo t'asiko to ye kin jere
K'emi irewesi maje ngbere itiju
Mashaallah
Gbogbo oun tase ladura k'olohun ose, K'oba olohun dawa loun k'ojo to lo o
Nigba t'aba lalafia kogbo tode
Loye ko fun wa loko ateni to nwaya o
Olohun la gbeke le o, ta doju ko
Ma f'asiko to ma peju k'oto muwon se
Asiko temi o f'ayo gba ire ayemi
Lasiko toto ati igba toye
Bimose nsin'lohun bo lojo ayemi o
Bo t'asiko to ye kin jere
K'emi irewesi maje ngbere itiju
Monpe allah
Onjeee
Emi npe allah
Onjemi
Monpe allah
Onjeee
Emi npe allah
Onjemi
Mo npe allahu personally
Allah wa ndami loun gradually
Mo ndupe f'olohun severally
Allah wa ndami loun constantly
Monpe allah
Onjeee
Emi npe allah
Onjemi
Nimose m'esin olohun seriously
Koba le funmi lesan to gradely
Olohun joo funmilayo to purely
Tikoni wa comparably
Monpe allah
Onjeee
Emi npe allah
Onjemi
Bimose fe lose se accordingly
Bee ni koma bamise continuously
Ony'ota bose nje mysteriously
Oore ile ayemi kopo kowa tangibly
Monpe allah
Onjeee
Emi npe allah
Onjemi
L'olohun mi ba s'ona tio nira
Olohun mi lo sona tio nira
Igba to rimi lole o, to nsannani, Lolohun mi ba sona tio nira
Naam
Mio jiyagbe mo r'ore gba nitemi
O s'aye funmi pe kin joko aga ni
P'oju orun t'eye fo lai fara kanra
Mio ni k'elomiran ma maga,
Oun lojumi se nrayo nitemi
Loje k'aye o ma gbami ejire
Igba to rimi lole o to nsannani
L'olohun mi ba sona tio nira
L'olohun mi ba s'ona tio nira
Olohun mi lo sona tio nira
Igba to rimi lole o, to nsannani, Lolohun mi ba sona tio nira
Béè!
Lasiko temi wa nladun bi oyin ni
Lsiko temi ko'rawo topo jo
Kofi temi di telomiran lowo
Bonsende ninu mi ma ndun si
Mowa dabi oba laarin awon ijoye
K'okikimi maa rele ko kan si ni K'irawo mi tun ma tan kaakiri lo
L'olohun mi ba s'ona tio nira
Olohun mi lo sona tio nira
Igba to rimi lole o, to nsannani, Lolohun mi ba sona tio nira
As'éyín tio bai tikaaaaaa
Yio j'eran tio tobi tio j'erin lo
As'éyín tio bai tiika
Yio j'eran tio tobi tio j'erin lo
Lolohun mi ba s'ona tio nira
Olohun mi lo sona tio nira
Igba to rimi lole o, to nsannani Lolohun mi ba sona tio nira
L'olohun mi ba s'ona tio nira
Olohun mi lo sona tio nira
Igba to rimi lole o, to nsannani, Lolohun mi ba sona tio nira
Allahu mi s'oore funmi topo o
Emi oni yalaimoore
Salekun oore lopolopo o
Emi oni salai dupe
Allahu mi s'oore funmi topo o
Emi oni yalaimoore
Salekun oore lopolopo o
Emi oni salai dupe
Shukuran
Ko bami nnuje se lon nfun mi layo o Lori ebi lori awon omo o
Mio m'akoba koje nri wahala o
Nise lo nfun mi nirorun
Wa salekun ore lopolopo o
Emi o ni salai dupe
Allahu mi s'oore funmi topo o
Emi oni yalaimoore
Salekun oore lopolopo o
Emi oni salai dupe
Haa!
Timo ba ranti ibi timo tinbo o
Omi a ma le simi loju
Se lorin ope a jade lenu
Lasiko yi tonse opo oore
Mo nireti ore lopolopo o
Emi o ni salai dupe
Allahu mi s'oore funmi topo o
Emi oni yalaimoore
Salekun oore lopolopo o
Emi oni salai dupe
Bee!
Gbogbo aye ngb'oore moma ri temi gba o
Kotun wa je koja si inira
Ope lo ma ni ka muwa o allah
Lemi muwa nwo tunbo ma du
Salekun oore lopolopo
Emi oni salai dupe
Allahu mi s'oore funmi topo o
Emi oni yalaimoore
Salekun oore lopolopo o
Emi oni salai dupe
Oriyomi mo mope wa
Enu ope mi o kan o
Mom tun dupe emi t'alafia ara
Mo dupe igbagbogbo ope mi o kan o
F'olohun tose iso e pelu aya o
Olohun tose ike e lori awon omo
Oriyomi mo mope wa
Enu ope mi o kan o
Mom tun dupe emi t'alafia ara
Mo dupe igbagbogbo ope mi o kan o
F'olohun tose iso e pelu aya o
Olohun tose ike e lori awon omo
Se mope lilo bibo eda laye owa labe iso o,
Security t'oba funmi o ju ti soldier lo
Iso eda yato si ti oba toda eda
Tor'awon ti a npe ni oluso awa
Ta wa loluso tonso awon naa gan o
Olohun tonso eda e ni ka gbojuleo
Koma ma se ka iso e lori kowa
Oriyomi mo mope wa
Enu ope mi o kan o
Mom tun dupe emi t'alafia ara
Mo dupe igbagbogbo ope mi o kan o
F'olohun tose iso e pelu aya o
Olohun tose ike e lori awon omo
Allah
Bukata mi at'omo mi ma fi won mi allah
Ma somi dotubante loju ebi mio
Koma dipe, kiki enu nikan loni afi koda ola
Ola ti kiitan londa o nsoni di yeye
Wa f'owo somo odo funmi, kin nna lona eto o
Olohun to nbashiri eda laye o
Ma dami da bukata wase opo oore
Oriyomi mo mope wa
Enu ope mi o kan o
Mom tun dupe emi t'alafia ara
Mo dupe igbagbogbo ope mi o kan o
F'olohun tose iso e pelu aya o
Olohun tose ike e lori awon omo
Ope kii sope emi nikan
Kajo ma du
At'emi atire nio
Kajo ma du
B'o lowo dupe alafia o
Kajo, ma du
Toba nsope owo made
Kajo ma du
Ope o koja omoniyan o
Kajo ma du
Koma si b'ose leje
Kajo ma du
Aye ope a pada yo
Kajo madu
Ao ni dupe tipatipa
Kajo, ma du
Ope kii sope emi nikan
Kajo ma du
At'emi atire nio
Kajo ma du
Written by: Oriyomi kehinde